Lafiaji Okuneye Bilikis

Láfíàjí Okùnẹ́yẹ Bilikis jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n ìlera, ọmọ bíbí Ìpínlẹ̀ Èkó.[1] A bí Bilikis ní ọjọ́ kejì oṣù kejì ọdún 1972 ní erékùṣù ìlú Èkó. Ó jẹ́ gíwá Ilé ẹ̀kọ́ olùkọ́ni àgbà ti Adéníran Ògúnsànyà College of Education‎.[2]

Awon itokasi àtúnṣe