Adeniran Ogunsanya College of Education
Adeniran Ogunsanya College of Education, tí àgékúrú rẹ̀ ń jẹ́ (AOCOED), jé ilé-ẹ̀kó gíga (Higher Education) tí ó wà ní ìlú Ọ̀tọ̀-Àwórì lábẹ́ ìjọba ìbílẹ̀ Ọ̀jọ́, Ìpínlé̀ Èkó.[1] ilé- ẹ̀kọ́ Adéníran Ògúnsànyà ń ṣètò ìmọ̀ ìkọ́ni gẹ́gẹ́ bí olùkọ́ tí ó sì ń pèsè ìwé ẹ̀rí 'Nigeria Certificate in Education' (NCE) àti ìmọ̀ ìkọ́ni tí ilé-ẹ̀kọ́ àgbà alákọ́kọ́ (undergraduate first degree), pẹ̀lú ìbáṣepọ̀ ilé-ẹ̀kọ́ àgbà ti ìpínlẹ̀ ( Èkìtì State University ) [2]
Adeniran Ogunsanya College of Education | |
---|---|
Motto | Knowledge, Culture and Service |
Motto in English | knowledge,culture and service |
Established | 1958 |
Type | Public |
Provost | Ojogbon Lafiaji Okuneye Bilikis |
Location | Oto-Awori, Lagos State, Nigeria |
Website | Official website |
Ìtàn ilé-ẹ̀kọ́ náà
àtúnṣeIlé-ẹ̀kọ́ gíga náà tí wọ́n kọ́kọ́ ń pè ní "ilé-ẹ̀kọ́ gíga ti ìpínlẹ̀ Èkó" (Lagos State College of Education), ni wọ́n dá sílẹ̀ ní ọdún 1958 gẹ́gẹ́ bí ilé-ẹ̀kọ́ àwọn olùkọ́ onípele kẹ́ta, tí wọ́n sì kọ́kọ́ gbà àwọn akẹ́kọ̀ọ́ tí ó tó Àádọ́sàán (90) ní ọdún àkọ́kọ́. Ní ọdún 1982, wọ́n gbé ilé-ẹ̀kọ́ náà kúrò ní Súrùlérè lọ sí Ọ̀tọ̀-Àwórì, látàrí àìtó àwọn ohun amáyé-dẹrùn ìgbà-lódé àti pípọ̀ tí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ń pọ̀ si lọ́dọọdún.
Lára àwọn lààmì-laaka tó ti jáde níbẹ̀
àtúnṣe- Kunle Ajayi
- Sarah Adebisi Sosan
- Sanai O. Agunbiade
Awon ile-eko mefa ti o wa ni inu ile-eko giga Adeniran Ogunsanya ni:
àtúnṣe- school of science
- school of education
- school of art and social science
- school of vocational and technical education
- school of early childhood and primary education
- school of language
Lára àwọn olùkọ́ tó gbajúmọ̀ níbẹ̀ ni
àtúnṣeẸ tún lè wo
àtúnṣe- List of schools in Lagos
- List of colleges of education in Nigeria
Àwọn ìtọ́ka sí
àtúnṣe- ↑ "About Us". Archived from the original on 6 August 2015. Retrieved 5 July 2015.
- ↑ "EKSU sandwich students warned against cultism". Daily Independent Nigeria. 27 March 2013. Archived from the original on 6 July 2015. Retrieved 5 July 2015.