Lágelú ni ìtàn sọ pe o da ìlú Ìbàdàn sílẹ̀. Ìtàn fi ye wa wípé ibi ti o di ìlú Ìbàdàn l'óde òní bẹ̀rẹ ni ọdun 1829. Ni àkókó yi, irúkèrúdò pọ ni gbogbo ilẹ̀ Yorùbá káàkiri, eyi ni o si fa ti jagunjagun ti a n pe ni Lágelú fi wa tẹdo si ìlú Ìbàdàn. Erongba Lágelú ni lati fi ṣe ibùdó fún awon jagunjagun.

ItokasiÀtúnṣe

[1]

  1. https://litcaf.com/ibadan-history/