Lagos State House of Assembly

Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin Ìpínlẹ̀ Èkó

Ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin Ìpínlẹ̀ Èkó ni ó wà ní olú-ilé ìjọba Ìpínlẹ̀ Èkó ní Aláùsá, Ìkẹjà. Ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin yìí wà lábẹ́ ìṣàkóso ẹgbẹ́ òṣèlu APC tí ó ń ṣe ìjọba [[Ìlú Èkó] lọ́wọ́lọ́wọ́. Ilé ìgbìmọ̀ méje ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ló ti wà, àkọ́kọ́ wáyé ní oṣù kẹwá ọdún 1979 tí èyí tó ń lọ lọ́wọ́lọ́wọ́ sì bẹ̀rẹ̀ ní ọjọ́ kẹfà oṣù kẹfà ọdún 2011.[1][2] Ogójì aṣojú ni ó wà ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin, méjì láti ìjọba ìbílẹ̀ kọ̀ọ̀kan ní Ìlú Èkó.

Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin Ìpínlẹ̀ Èkó
Coat of arms or logo
Type
Type
kupusa yusa
Leadership
Olórí
Mubashiru Obasa, APC
Structure
SeatsOgójì
Length of term
Ọdún mẹ́rin
Meeting place
Ìlú Èkó

Olórí ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin lọ́wọ́ lọ́wọ́ ni Rt. Hon Mudashiru Ọbasá tí ó sì jẹ́ ẹni àkọ́kọ́ tí wọ́n maa yàn sí ipò yìí lẹ́ẹ̀mẹta.[2][3]

Àwọn ìtọ́kasí àtúnṣe

  1. "The Lagos State House of Assembly". Library of Congress Africa Pamphlet Collection - Flickr. Retrieved 2014-05-12.  More than one of |accessdate= and |access-date= specified (help)[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  2. 2.0 2.1 Ikuforiji, Adeyemi. "Lagos State House of Assembly". Archived from the original on 2016-10-23. Retrieved 2016-10-12. 
  3. "Lagos State House of Assembly". Archived from the original on 2016-03-04. Retrieved 2016-10-12.