Laide Adewale

Laide Adewale (tabi Uncle Laide 1944 - 17 May, 2007) je osere ori itage ati oluko omo ile Naijiria, osise ni eka-eko Dirama ni OAU, Ile-Ife ki o to se alaisi ni ojo ketadinlogun, osu karun-un odun 2007 (17/5/2007). Odun 1944 ni won bi i. Odun 1974 ni o bere ise ni eka-eko yii leyin igba ti o ti feyin ti lenu ise olopaa. Inu ere ti o ti gbajumo ju ni Kurumi ati Afonja. Odun 2006 ni o feyinti lenu ise ni Dramatic Arts Dept., OAU, Ife. Ki Olorun te e si afefe rere.

Uncle laide.jpg


ItokasiÀtúnṣe