Laingsburg South Africa

Laingsburg jé ìlù tí ò wà ní Western Cape ní apá Gúsù ìlè Africa. Ó jé ìlú tí ètò ǹkán ọ̀gbìn tí gbìlẹ̀. Ó parun nípasẹ̀ ìkún omi tí ó ṣẹlẹ̀ ni ọdún 1981.

Laingsburg
A view of Laingsburg
A view of Laingsburg
Lua error in Module:Location_map at line 464: Unable to find the specified location map definition. Neither "Module:Location map/data/South Africa Western Cape" nor "Template:Location map South Africa Western Cape" exists.
Coordinates: 33°11′42″S 20°51′33″E / 33.19500°S 20.85917°E / -33.19500; 20.85917Coordinates: 33°11′42″S 20°51′33″E / 33.19500°S 20.85917°E / -33.19500; 20.85917
CountrySouth Africa
ProvinceWestern Cape
DistrictCentral Karoo
MunicipalityLaingsburg
Area
 • Total723.72 km2 (279.43 sq mi)
Population
 (2011)[1]
 • Total5,667
 • Density7.8/km2 (20/sq mi)
Racial makeup (2011)
 • Black African8.2%
 • Coloured82.3%
 • Indian/Asian0.3%
 • White8.5%
 • Other0.7%
First languages (2011)
 • Afrikaans93.6%
 • English1.7%
 • Xhosa1.6%
 • Other3.1%
Time zoneUTC+2 (SAST)
Postal code (street)
6900
PO box
6900
Area code023

Ìwọ̀n ilé

àtúnṣe

Laingsburg wá ní N1 route,ní Lat:-33.20,Long:20.85 ní ìwò òrùn cape ni South Africa.

Ìlú yìí wá ní Great Karoo, ìlú aṣálè ti South Africa. Òjò tí ó máà ro ní ọdọọdún jẹ́ 150mm lọ́dún. Ìgbà ẹrùn máa ń gbóná gidi. Ìgbà òjò uì máà tutù gan pelu yìnyín ni àyíká wọn.Seweweekspoort pass wá ní R323 tí apá Gúsù ìlú náà .

Àwọn ìtókasí

àtúnṣe
  1. 1.0 1.1 1.2 1.3 "Main Place Laingsburg". Census 2011.