Lake Ahémé
Lake Ahémé jẹ́ adágún odò kejì tí ó tóbi jùlọ ní Benin, ibi tí ó gbà tó 78 square kilometres (30 sq mi) ní ìgbà ẹ̀rùn, ó sì ma ń tó 100 square kilometres (39 sq mi) nígbà òjò.[2] Gígùn adágún odò náà tó 24 kilometres (15 mi) fífẹ̀ rẹ̀ sì tó 3.6 kilometres (2.2 mi).[1] Odò Couffo ṣàn sínú àríwá ìwọ̀ oòrùn náà.[2]
Lake Ahémé | |
---|---|
Location | Gúúsù ìwọ̀ oòrùn Benin |
Coordinates | 6°29′42″N 1°58′30″E / 6.495°N 1.975°ECoordinates: 6°29′42″N 1°58′30″E / 6.495°N 1.975°E |
Primary inflows | Couffo River |
Primary outflows | Aho Channel |
Basin countries | Benin |
Max. length | 24 km (15 mi)[1] |
Max. width | 5.5 km (3.4 mi)[1] |
Surface area | 78–100 km2 (30–39 sq mi)[2] |
Surface elevation | 3–5 m (9.8–16.4 ft)[1] |
Settlements | Agatogbo, Agbanto, Akodéha, Bopa, Dekanmè, Kpomassè, Possotomè, Tokpa-Domè |
Ẹ̀yà Pedah àti Ayizo ni àwọn ẹ̀yà méjì gbòógì tí ó ń gbé tí etí groups adágún Ahémé.[2][3] Iṣẹ́ apẹja àti àgbẹ̀ ni iṣẹ́ tí wọ́n ṣe ní agbẹ̀gbẹ̀ náà.[1][2] Àwọn oríṣi ẹja tí ó wà ní adágún Ahémé tó ọ̀kànlẹ́làádọ́rin.[4][5]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 1.2 1.3 1.4 Hughes, R. H.; Hughes, J. S. (1992). A directory of African wetlands. IUCN. ISBN 2-88032-949-3. https://books.google.com/books?id=VLjafeXa3gMC&pg=PA305.
- ↑ 2.0 2.1 2.2 2.3 2.4 Dangbégnon, Constant (2000). Governing Local Commons: What Can be Learned from the Failures of Lake Aheme's Institutions in Benin?. Eighth Biennial Conference of the International Association for the Study of Common Property. Bloomington, Indiana.
- ↑ Houngnikpo, Mathurin C.; Decalo, Samuel (2013). Historical Dictionary of Benin. Rowman & Littlefield. ISBN 978-0810871717. https://books.google.com/books?id=0yGPTsRubWEC. Retrieved 28 July 2016.
- ↑ "Basse Vallée du Couffo, Lagune Côtiere, Chenal Aho, Lac Ahémé". Retrieved 28 July 2016.
- ↑ "Présentation". Archived from the original on 18 August 2016. Retrieved 28 July 2016.