Lamidi Adeyemi III
A bí Aláàfin Ọ̀yọ́, Ọba Làmídì Ọláyíwọlá Adéyẹmí III ní ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dógún oṣù kẹwàá, (1938-2022). Ó jẹ́ Ọba tó wà lórí ìtẹ́ Aláàfin lọ́wọ́lọ́wọ́ ní ìlú Ọ̀yọ́.
HRH Oba Lamidi Adeyemi III | |
---|---|
Alaafin of Oyo | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 18 November 1970 | |
Asíwájú | Gbadegesin Ladigbolu II |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 15 Oṣù Kẹ̀wá 1938 |
Website | alaafin-oyo.org/main/ |