Ẹ̀rọ Ìmúsáré Hádrónì Gbàngbà

totem ap cover
(Àtúnjúwe láti Large Hadron Collider)

Coordinates: 46°14′N 06°03′E / 46.233°N 6.050°E / 46.233; 6.050

Àdàkọ:Hadron colliders

Nínú ọ̀dẹ̀dẹ̀ ẹ̀rọ ìmúsáré
Large Hadron Collider
(LHC)
LHC experiments
ATLASA Toroidal LHC Apparatus
CMSCompact Muon Solenoid
LHCbLHC-beauty
ALICEA Large Ion Collider Experiment
TOTEMTotal Cross Section, Elastic Scattering and Diffraction Dissociation
LHCfLHC-forward
MoEDALMonopole and Exotics Detector At the LHC
LHC preaccelerators
p and PbLinear accelerators for protons (Linac 2) and Lead (Linac 3)
(not marked)Proton Synchrotron Booster
PSProton Synchrotron
SPSSuper Proton Synchrotron

Ẹ̀rọ Ìmúsáré Hádrónì Gbàngbà tabi Large Hadron Collider (LHC) ni ero imusare eruku pelu okun totobijulo ati togajulo lagbaye. Ó jẹ́ kíkọ́sókè látọwọ́ CERN láti ọdún 1998 dé 2008, pẹ̀lú èrò láti gba àwọn aṣefísíksì láyè láti ṣe àdánwò ìsọtẹ́lẹ̀ àwọn orísi àròjinlẹ̀ físíksì eruku àti físíksì olókun-gíga, àti àgàgà láti wá bọ́yá bósónì Higgs wà lóòótọ́[1] àti orísirísi àwọn eruku tuntunàjọbáramu adárajùlọ ṣe àsọtẹ́lẹ̀.[2] Ìrètí ni pé LHC yíò wá ìdáhùn is expected to address some of the ọ̀pọ̀ àwọn ìbérè inú físíksì, nípa èyí láti mú ìlọsíwájú bá òye àwọn òfin àdánidá jínjnlẹ̀. Ó ní ẹ̀rọ ìwárí mẹ́fà tí ìkọ̀ọ̀kan wà fún ìwàdìí ohun pàtó kan.Itokasi àtúnṣe

  1. "Missing Higgs". CERN. 2008. Retrieved 2008-10-10. 
  2. "Towards a superforce". CERN. 2008. Retrieved 2008-10-10.