Lateef Káyọ̀dé Jákàńdè, (tí a bí ní Ọjọ́ kẹtàdínlógún, oṣù kẹfà ọdún 1929) jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà àti Gómìnà Ìpínlẹ̀ Èkó tẹ́lẹ̀ ati alákoso ètò isẹ́ abẹ́lé lábẹ́ ìjọba Sani Abacha.[1]

Lateef Kayode Jakande
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Èkó
Lórí àga
Oṣù kẹwá ọdún 1979 – Oṣù kejìlá 1983
AsíwájúEbitu Ukiwe
Arọ́pòGbolahan Mudasiru
Alakoso Ise-abele
Lórí àga
Oṣù kọkànlá ọdún 1993 – Oṣù kẹjọ ọdún 1998
Personal details
Ọjọ́ìbíỌjọ́ kẹtàlélógún oṣù keje ọdún
Ìpínlẹ̀ Èkó, Nàìjíríà
OccupationOníwé ìròyìn

Àwọn ìtọ́kasíÀtúnṣe

  1. "Carry On My Boys". Google Books. Retrieved 2018-07-23.