Lateef Olufemi Okunnu Àdàkọ:Post-nominals tí wọ́n bí ní ọjọ́ kọkàndínlógún òṣù kejì ọdún 1933 jẹ́ agbẹjọ́rò àgbà ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti Alága àgbà fún ilé-ẹ̀kọ́ ọ̀gbìn University of Agriculture, Makurdi.[1][2]

Lateef Olufemi Okunnu
Pro-chancellor of the University of Agriculture, Makurdi
In office
1982–1984
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí19 Oṣù Kejì 1933 (1933-02-19) (ọmọ ọdún 91)
Lagos State, Nigeria
Ẹgbẹ́ olóṣèlúIndependent

Ìgbésí ayé àti iṣẹ́ rẹ̀

àtúnṣe

Wọ́n bí Lateef Okunu ní ọjọ́ kọkàndínlógún òṣù kejì ọdún 1933 ní ìlú Èkó. Ó lọ sílé ẹ̀kó alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ti Ansarudeen, tí ó wà ní Alakoro láàrín ọdún 1938 sí 1947. Tí ó sì tún lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ Kings College láàrín ọdún 1938 sí 1953. [3][4] Ní ọdún 1956, ó wọ ilé-ẹ̀kọ́ University of London níbi tí ó ti kẹ́kọ́ gbiyè akọ́kọ́ nínú ìmọ̀ òfin tí wọ́n sì gbàá wọlé gẹ́gẹ́ bí amòfin agbẹjọ́rò ní ọdún 1960, wọ́n sì tún fi jẹ Alákòóso ìjọba apápọ̀ fún iṣẹ́ àti ilégbèé. [5][6]Ó ṣakóso gẹ́gẹ́ bí adarí ní ipò yí fún ọdún méje tí sáà rẹ̀ sì tẹnubepo ní ọdún 1974. Wọ́n t tún yàn án gẹ́gẹ́ bí olùgbani nímọ̀ọ̀ràn amòfin fún ẹgbẹ́ He served in this capacity for seven years, a tenure that ended in 1974 National Party of Nigeria (N.P.N.) ní ọdún 1981.[7]

Iṣẹ́ tí ìjọba yàn án

àtúnṣe

Ìjọba yàn án gẹ́gẹ́bí agbẹnusọ fún orílẹ̀-èdè Nàìjíríà nínú àpérò Organisation of African Unity Consultative Committee nípa sísọ̀rọ̀ lórí ọ̀rọ̀ àlááfíà látàrí ogun abẹ́lé tí ó wáyé lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà láàrín ọdún 1968 àti ti ọdún 1969, Ìjọba tún yàn án gẹ́gẹ́bí agbẹnusọ fún orílẹ̀-èdè Nàìjíríà nínú àpérò O.A.U. Ministerial Conference. Ní ọdún 1980, òun ni ó ṣe agbẹnusọ fún orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní inú àpérò U.N.O. Lẹ́yìn náà ni wọ́n yàn án gẹ́gẹ́ bí Alákòóso àgbà fún ilé-ẹ̀kọ́ fáfitì University of Agriculture, Makurdi ní ọdún 1982.

Awọn amì-ẹ̀yẹ àti ìfisọrí rẹ̀

àtúnṣe
  • Senior Advocate of Nigeria (S.A.N)
  • Commander of the Order of the Republic of Niger (CON)
  • Commander de I, Ordre National Du Dahomey and Commander National Order of Togo.
  • He was awarded with an honorary doctorate degree during the 50th convocation ceremony of the University of Lagos [1][Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]

"Olúfẹ́mi" tí ó túmọ̀ sí Oluwaẹ́mi [8]

Àwọn itọ́kasí

àtúnṣe
  1. "I was taught to respect opposing views - Lateef Okunnu - Vanguard News". Vanguard News. Retrieved 28 November 2014. 
  2. "Aregbesola backs Jihad, flays Boko Haram attacks". The Punch - Nigeria's Most Widely Read Newspaper. Archived from the original on 5 December 2014. Retrieved 28 November 2014.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  3. "Nigeria's first Ansar-ud-den College of Education clocks 10, says school not for Musilms [sic] alone". DailyPost Nigeria. Retrieved 28 November 2014. 
  4. RapidxHTML. "The Nigeria Academy of Engineering :: promoting excellence in technology and engineering training and practice to ensure the technological growth and economic development of Nigeria". Archived from the original on 6 December 2014. Retrieved 28 November 2014. 
  5. Amidu Arije. "‘Boko Haram doesn’t represent Islam’". Retrieved 28 November 2014. 
  6. "[General] The Femi Okunnu Interview [Part 1: Dangers of Zoning]". Village Square Forum. Archived from the original on 4 December 2014. Retrieved 28 November 2014. 
  7. "Olufemi Okunnu kills federation - The Nigerian Eye Newspaper: Breaking news in Nigeria as well as Nigerian News, ghana news, information and opinion on sports, business, politics and more from Nigeria's most read newspaper.". Archived from the original on 4 December 2014. Retrieved 28 November 2014. 
  8. "Olufemi". Behind the Name. Retrieved December 20, 2014. 

Àdàkọ:Authority control