Laycon
(Àtúnjúwe láti Laycon (Ọlámilékan Agbélẹ̀ṣe))
Ọlámilékan Moshood Agbélẹ̀ṣe tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Laycon ní woọ́n bí lọ́jọ́ kẹjọ oṣù kọkànlá ọdún 1993,(8 November, 1993) jẹ́ gbajúmọ̀ olùdíje tí ó borí ìdíje ètò-ìgbafẹ́ ẹ̀rọ tẹlifíṣàn, Big Brother Naija (ìpele karùn-ún), ó jẹ́ olórin-tàkasúfèé àti oǹkọ̀wé orin ọmọ orilẹ̀-èdè Nàìjíríà
Laycon | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Ọlámilékan Moshood Agbélẹ̀ṣe 8 Oṣù Kọkànlá 1993 Ìpínlẹ̀ Èkó, Nàìjíríà |
Iṣẹ́ |
|
Musical career | |
Irú orin | |
Instruments | Vocals |
Years active | 2016–present |
Labels | Fierce Nation |
Associated acts | |
Ìgbésí-ayé àti ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀ láti ìbẹ̀rẹ̀
àtúnṣeWọ́n bí Ọlámilékan Moshood Agbélẹ̀ṣe tí gbogbo ènìyàn mọ́ sí Laycon sí ìlú Èkó, ní Nàìjíríà.[1][2] ṣùgbọ́n, ó jẹ́ ọmọ bibi ìlú Bájùwẹ̀n, ní Ọdẹdá ní Ìpínlẹ̀ Ògùn.[3][4]
Ó kàwé gbàwé ẹ̀rí nínú ìmọ̀ philosophy ní University of Lagos lọ́dún 2012 sí 2016.[5][6][7]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Zawadi, Lucy. "Olamilekan "Laycon" Agbeleshe bio: BBNaija 2020 contestant profile". Legit.ng. Retrieved 28 September 2020.
- ↑ Olukoya, Samuel (26 September 2020). "Laycon Bbnaija Biography, Career and Health Issue". Investors King. Retrieved 28 September 2020.
- ↑ Ogunnaike, James (24 September 2020). "BBNAIJA: Ogun youths march for Laycon, give out airtime for voting". Vanguard Newspaper. Retrieved 28 September 2020.
- ↑ Agbana, Rotimi (25 September 2020). "BBNAIJA: Ogun Youths Drum Support For Laycon". The Independent Newspaper. Retrieved 28 September 2020.
- ↑ Adekanye, Modupeoluwa (20 July 2020). "Who is Laycon, BBNaija’s Diamond In The Rough?". The Guardian Newspaper. Archived from the original on 15 September 2020. Retrieved 28 September 2020.
- ↑ Motolani, Alake (21 July 2020). "BBNaija 2020: Who is Laycon?". Pulse Nigeria. Retrieved 28 September 2020.
- ↑ Preye, Campbell (26 September 2020). "Big Brother Naija: Icons Emerge". P.M. News. Retrieved 28 September 2020.