Lee Myung-bak (pípè /ˌliː ˌmjʊŋˈbæk/; Pípè ní èdè Kòréà: [i.mʲʌŋ.bak̚]; ojoibi 19 December 1941 ni Osaka, Japan) je oloselu omo Korea to je Aare orile-ede Guusu Korea lowolowo lati 2002. Ki o to bo si ipo aare, o je oludari agba ile-ise Hyundai Engineering and Construction, ati baale ilu Seoul.

Lee Myung-bak
Hangul: 이명박
Hanja: 李明博
President of South Korea
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
25 February 2008
Alákóso ÀgbàHan Seung-soo
Chung Un-chan
AsíwájúRoh Moo-hyun
Mayor of Seoul
In office
1 July 2002 – 30 June 2006
AsíwájúGoh Kun
Arọ́pòOh Se-hoon
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí19 Oṣù Kejìlá 1941 (1941-12-19) (ọmọ ọdún 82)
Osaka, Japan
Ẹgbẹ́ olóṣèlúGrand National Party
(Àwọn) olólùfẹ́Kim Yun-ok
Korean name
Hangul이명박
Revised RomanizationI Myeong-bak
McCune–ReischauerYi Myŏngpak
Pen name
Hangul일송
Revised RomanizationIlsong
McCune–ReischauerIlsong
Japanese name:
Tsukiyama Akihiro (?)