Chung Un-chan

Chung Un-chan (Abíi ní February 29, 1946 ní Gongju, Chungcheongnam-do, Korea Guusu) ó jẹ́ Alákoso Àgbà ilẹ̀ Korea Guusu láti ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n (29) Oṣù Kẹsàn-an (September)ní 2009 dé ọjọ́ kọkànlá (11) oṣù kẹjọ (Agust)(2010). Ó jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n ní Seoul National University láti 19782009, kí wọn ó tó yan-àn gẹ́gẹ́ bíi alákoso Àgbà, níbi tí ó ti jẹ ààrẹ yunifásítì náà láti July 2002 dè July 2006.

Chung Un-chan
정운찬
鄭雲燦
ChungUnChan(060515)Cropped.jpg
Prime Minister of South Korea
In office
29 September 2009 – 11 August 2010
ÀàrẹLee Myung-bak
AsíwájúHan Seung-soo
Arọ́pòYoon Jeung-hyun (Acting)
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí29 Oṣù Kejì 1948 (1948-02-29) (ọmọ ọdún 73)
Gongju, Korea (now South Korea)
Ẹgbẹ́ olóṣèlúIndependent
Alma materSeoul National University
Miami University
Princeton University
ProfessionEconomist
Professor
Korean name
Hangul정운찬
Revised RomanizationJeong Un-chan
McCune–ReischauerChŏng Unch'an


Ìtọ́kasíÀtúnṣe