Léopold Sédar Senghor
(Àtúnjúwe láti Leopold Sedar Senghor)
Léopold Sédar Senghor (9 October 1906 – 20 December 2001) je akoewi, oloselu ati ajiro asa omo ile Senegal to gori ipo gege bi Aare akoko orile-ede Senegal lati 1960 de 1980. O je ikan pataki lara awon onimo ijinle ni ile Afrika.
Léopold Sédar Senghor | |
---|---|
Àarẹ ilẹ̀ Senegal | |
In office 6 September 1960 – 31 December 1980 | |
Asíwájú | Ijoba Alamusin ile Faranse |
Arọ́pò | Abdou Diouf |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Joal, Senegal | Oṣù Kẹ̀wá 9, 1906
Aláìsí | December 20, 2001 Normandy, France | (ọmọ ọdún 95)
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Senegalese Democratic Bloc |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |