Liam Neeson

Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America

William John Neeson Àdàkọ:Post-nominals (born 7 June 1952) jẹ́ òṣèré ọmọ orilẹ̀-èdè Northern Ireland.[3] Ó ti gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ oríyìn bi àmì-ẹ̀yẹ Golden Globe Awards mẹ́ta àti Tony Awards méjì. Ní ọdún 2020, ó jẹ́ ipò keje nínú àwọn òṣèré tí The Irish Times so wípé ó gbajúmọ̀ jùlọ.[4] Wọ́n fún Neeson ní ipò Officer of the Order of the British Empire (OBE) ní ọdún 2000.[5]

Liam Neeson
OBE
Neeson ní ọdún 2012
Ọjọ́ìbíWilliam John Neeson
7 Oṣù Kẹfà 1952 (1952-06-07) (ọmọ ọdún 72)
Ballymena, Northern Ireland
Iṣẹ́Actor
Ìgbà iṣẹ́1976–present
WorksFull list
Olólùfẹ́
Natasha Richardson
(m. 1994; died 2009)
Alábàálòpọ̀Helen Mirren (1980–1985)[1][2]
Àwọn ọmọ2, including Micheál Richardson
AwardsFull list

Ní ọdún 1976, Neeson darapọ̀ mọ́ Lyric Players' Theatre ní ìlú Belfast fún ọdún méjì. Àwọn eré tí ó ti kọ́kọ́ farahàn ni Excalibur (1981), The Bounty (1984), The Mission (1986), The Dead Pool (1988), and Husbands and Wives (1992).

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Helen Mirren Says She and Ex Liam Neeson 'Loved Each Other' But 'Were Not Meant to Be Together'". 2022-11-22. Retrieved 2023-01-28. 
  2. "Liam Neeson Recalls First Falling for Former Flame Helen Mirren: 'I Was Smitten'". 2018-01-19. Retrieved 2023-01-28. 
  3. "Liam Neeson promotes Northern Ireland tourism". BBC News. 10 March 2014. https://www.bbc.co.uk/news/uk-northern-ireland-26504259. 
  4. Clarke, Donald; Brady, Tara (13 June 2020). "The 50 greatest Irish film actors of all time – in order". The Irish Times. https://www.irishtimes.com/culture/film/the-50-greatest-irish-film-actors-of-all-time-in-order-1.4271988. 
  5. Wilson, Jamie (31 December 1999). "Top billing at last for veteran entertainers; Showbusiness Awards for Elizabeth Taylor and Shirley Bassey". The Guardian (London): p. 4.