Àtòjọ àwọn Ààrẹ ilẹ̀ Rùwándà

ojúewé àtojọ Wikimedia
(Àtúnjúwe láti List of Presidents of Rwanda)

Àyọkà yìí ṣe àtòjọ orúkọ àwọn Ààrẹ ilẹ̀ Rùwándà láti ìgbà tí wọ́n dá ipò náà sílẹ̀ ní ọdún 1961 (nígbà Ìjídìde àwọn ará Rùwándà), títí di òní. Gẹ́gẹ́ bí òfin-ìbágbépọ̀ ṣe lànà rẹ̀, iṣẹ́ Ààrẹ ni gẹ́gẹ́bí olórí orílẹ̀-èdè ilẹ̀ Rwanda, ó sì ní agbára aláṣe tó pọ̀.[2] Wọ́n dìbò yan sí ipò ààrẹ yìí fún ọdún méje,[3] Ààrẹ yíò si yan Alákóso Àgbà àti gbogbo àwọn ará Kábínẹ́ẹ̀tì rẹ̀.[4]

Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Rùwándà
President of the Republic of Rwanda
Flag of the President
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Paul Kagame

since 24 March 2000
ResidenceVillage Urugwiro, Kacyiru, Kigali
Iye ìgbà7 years
Ẹni àkọ́kọ́Dominique Mbonyumutwa
Formation28 January 1961
Owó osù85,000 USD annually[1]

Àwọn mẹ́rin ló ti jẹ Ààrẹ ilẹ̀ Rùwándà (láì ka àwọn Adípò Ààrẹ). Ààrẹ lọ́wọ́lọ́wọ́ ni Paul Kagame, láti 24 March 2000.

Political parties
Other factions
Status
  •   Acting President

List of officeholders

àtúnṣe
No. Portrait Name
(Birth–Death)
Elected Term of office Ethnic group Political party Prime Minister(s)
Took office Left office Time in office
Republic of Rwanda (part of Ruanda-Urundi)
  Dominique Mbonyumutwa
(1921–1986)
28 January 1961 26 October 1961 271 days Hutu Parmehutu Kayibanda
1   Grégoire Kayibanda
(1924–1976)
1961 26 October 1961 1 July 1962 248 days Hutu Parmehutu Himself
Republic of Rwanda (independent country)
(1)   Grégoire Kayibanda
(1924–1976)
1965
1969
1 July 1962 5 July 1973
(deposed.)
11 years, 4 days Hutu Parmehutu Position abolished
2   Juvénal Habyarimana
(1937–1994)[lower-alpha 1]
1978
1983
1988
5 July 1973 6 April 1994
(assassinated.)
20 years, 275 days Hutu Military /
MRND
Nsanzimana
Nsengiyaremye
Uwilingiyimana
  Théodore Sindikubwabo
(1928–1998)
8 April 1994 19 July 1994
(ousted.)[lower-alpha 2]
102 days Hutu MRND Kambanda
3   Pasteur Bizimungu
(1950–)
19 July 1994 23 March 2000
(resigned.)
5 years, 248 days Hutu RPF Twagiramungu
Rwigema
Makuza
4   Paul Kagame
(1957–)
2000
2003
2010
2017
24 March 2000 22 April 2000 24 years, 285 days Tutsi RPF Makuza
Habumuremyi
Murekezi
Ngirente
22 April 2000 Incumbent

Latest election

àtúnṣe
Candidate Party Votes %
Paul Kagame Rwandan Patriotic Front 6,675,472 98.79
bgcolor="Àdàkọ:Independent (politician)/meta/color"| Philippe Mpayimana Independent 49,031 0.73
Frank Habineza Democratic Green Party of Rwanda 32,701 0.48
Invalid/blank votes 12,310
Total 6,769,514 100
Registered voters/turnout 6,897,076 98.15
Source: NEC Rwanda



  1. "Top 15 Highest Paid African Presidents 2017". 15 December 2016. Archived from the original on 22 September 2019. Retrieved 27 May 2020. 
  2. CJCR 2003, article 117.
  3. CJCR 2003, articles 100–101.
  4. CJCR 2003, article 116.


Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref> tags exist for a group named "lower-alpha", but no corresponding <references group="lower-alpha"/> tag was found