Orílẹ̀-èdè China ní èbúté ọkọ̀ ojú-omi tí ó jẹ́ gbogbo gbo tí ó tó mẹ́rìnlélọ́gbọ̀n, nígbà tí wọ́n ní àwọn èbúté kéréje-kéréje tí wọ́n tó ẹgbẹ̀rún méjì lápapọ̀, yàtọ̀ sí àwọn èbúté tí wọ́n jẹ́ gbajú-gbajà bí:Shanghai, Nanjing ati Nantong pẹ̀lú along èbúté Yangtze ati Guangzhou tí wọ́n wà ní ìtòsí odò Delta tí ó wọ òkun Yellow sea (Bo Hai), Taiwan straits, Pearl river àti South China Sea. Nígbà tí àwọn tó kù wà ní ìpasẹ̀ àwọn odò kékèké ti wọ́n wà ní ilẹ̀ China.[1] Púpọ̀ nínú àwọn ìlú ńlá ńlá tí wọ́n wà ní China náà ni wọ́n ní àwọn èbúté tí wọ́n ń ṣàmúlò.[2]

Àwọn èbúté tí wọ́n jẹ́ gbogbo gbò àtúnṣe

Àwọn èbúté tí a fe mẹ́nu bá wọ̀nyí ni wọ́n wà ní apá Gúsù sí àríwá ìlú [[Fuji]:[1]

1. Dalian 2. Yingkou 3. Jinzhou 4. Qinhuangdao 5. Tianjin 6. Yantai 7. Weihai 8. Qingdao 9. Rizhao 10. Lianyungang 11. Nantong 12. Zhenjiang 13. Jiangyin 14. Nanjing 15. Shanghai 16. Ningbo 17. Zhoushan 18. Taizhou (ó wà ní apá gúsù ìlú Wenzhou) 19. Wenzhou 20. Taizhou (ó wà ní apá àríwá ìlú Wenzhou ) 21. Changle 22. Quanzhou 23. Xiamen 24. Shantou 25. Jieyang 26. Guangzhou 27. Zhuhai 28. Shenzhen 29. Zhanjiang 30. Beihai 31. Fangchenggang 32. Haikou 33. Basuo 34. Sanya

Kìkọ́ èbúté ati àwọn ẹrù àtúnṣe

Èbúté ọkọ̀ ojú-omi ilẹ̀ China fàyè gba kí wọ́n ma gbé àwọn nkan bíi èédú, irin tútù,àgbàdo ati àwọn nkan óunjẹ ẹlẹ́yọ tí wọ́n ti dé pa sínú agolo kọ̀nténà, kí wọ́n lè ma wọlé tàbí jáde láti inú omi tí orí ilẹ̀ ati láti orí ilẹ̀ bọ́ sínú agbami òkun China kọ́ àwọn èbúté wọn láti lè mú kí gbígbé àwọn agolo kọ̀nténà ó rọrùn. Bákan náà ni wọ́n wọ́n kọ́ èbúté kan àrá ọ̀tọ̀ sí àwọn agbègbè bíi: Dalian, Tianjin, Qingdao, Shanghai, Ningbo, Xiamen ati Shenzhen, kí wọ́n lè ma gbé jáde tàbí wọlé àwọn agolo kọ̀nténà wọ inú àwọn ọkọ̀ tí wọ́n ń rin lábẹ́ omi, èyí ni ó sì mú kí àwọn èbúté ilẹ̀ China wọ́nyí ó ní akòjọ àwọn agolo kọ̀nténà tí ó pọ̀jù lọ ní agbáyé. Ẹ̀wẹ̀, wọ́n tún ti ṣí èbúté nla kan tí wọ́n kọ́ sí ìsàlẹ̀ omi tí wọ́ pe orúkọ rẹ̀ ní Yangshan tí ó wà ní ẹkún gúsù sí ìlà Oòrùn ìlú Shanghai. Wọ́n ti ṣe àfikún sí gbígbé àwọn èròjà tí a mẹ́nu bà lókè yí nípa fífẹ àwọn èbúté náà siwájú si, kódà ó ti lè gbé nkan bí epo rọ̀bì pẹ̀lú.

Èbúté agbègbè tàbí ẹkún Fujian àtúnṣe

Èbúté agbègbè tàbí ẹkún Guangdong àtúnṣe

Èbúté agbègbè tàbí ẹkún Hainan àtúnṣe

Èbúté agbègbè tàbí ẹkún Hebei àtúnṣe

Èbúté agbègbè tàbí ẹkún Hong Kong àtúnṣe

Èbúté agbègbè tàbí ẹkún Jiangsu àtúnṣe

Èbúté agbègbè tàbí ẹkún Liaoning àtúnṣe

Èbúté agbègbè tàbí ẹkún Macau àtúnṣe

Èbúté agbègbè tàbí ẹkún Shandong àtúnṣe

Èbúté agbègbè tàbí ẹkún Shanghai àtúnṣe

Èbúté agbègbè tàbí ẹkún Tianjin àtúnṣe

Èbúté agbègbè tàbí ẹkún Zhejiang àtúnṣe

Ẹ tún lè wo àtúnṣe

Àwọn itọ́ka sí àtúnṣe

  1. 1.0 1.1 "Ports in China". fujitrading.co.jp. Fuji trading. Retrieved 9 September 2016. 
  2. "Chna - Economy". Washington post. 8 September 2016. https://www.washingtonpost.com/wp-srv/world/countries/china.html. 

Àdàkọ:Ports of China Àdàkọ:Ports and harbors

Àdàkọ:Transport in China Àdàkọ:Economy of China