Lola Shoneyin
Lola Shoneyin (tí orúkọ àbísọ rẹ̀ ń jẹ́ Titilola Atinuke Alexandrah Shoneyin; ni wọ́n bí ni 26 February 1974, ní ìlú Ìbàdàn, ní Nàìjíríà) jẹ́ akéwì àti òǹkọ̀wé[1] tó ṣe àtẹ̀jáde ìwé àkọ́kọ́ rẹ̀, tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ The Secret Lives of Baba Segi's Wives, ní UK, ní oṣù May ọdún 2010.[2] Shoneyin gbajúmọ̀ fún àwọn ewì rẹ̀ tó tayọ, ó ti kọ ewì mẹ́ta.[3] Ìṣọwọ́kọ̀wé rẹ̀ jẹ mọ́ ọ̀rọ̀-ìbálòpọ̀ obìnrin àti ìpèníjà tó jẹ́ mọ́ ilẹ̀ Afirika.[4] Ní April 2014, wọ́n dárúkọ rẹ̀ ní Hay Festival's Africa39 mọ́ àwọn òǹkọ̀wé ilẹ̀ Afirika tí ò tí ì wọ ọmọdún ogojì, pẹ̀lú tálẹ́ǹtì láti ṣàtúnṣe sí àwọn lítíréṣọ̀ ilẹ̀ Afirika.[5] Lola gba ẹ̀bùn PEN Award ní America[6] bákan náà ni ó gba ti Ken Saro-Wiwa Award fún ìtàn-àròsọ ní Nàìjíríà.[7] Ó wà lára àwọn tó máa gba ẹ̀bùn Orange Prize ní UK fún ìtàn-àròsọ àkọ́kọ́ rẹ̀, The Secret of Baba Segi's Wives, ní ọdún 2010.[8] Ìlú Eko ní Nàìjíríà ni ó ń gbé, níbi tíh ó ti máa ń ṣe Aké Arts and Book Festival ní ọdọọdún.[9] Ní ọdún 2017, Brittle Paper sọ ọ́ ní African Literary Person of the Year.[10]
Lola Shoneyin | |
---|---|
Lola Shoneyin 2015 | |
Ọjọ́ìbí | Titilola Atinuke Alexandrah Shoneyin 26 Oṣù Kejì 1974 Ibadan, Oyo State, Nigeria |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian / British |
Iṣẹ́ | Author |
Olólùfẹ́ | Olaokun Soyinka |
Parents |
|
Àwọn olùbátan | Abraham Olayinka Okupe (Grandfather) |
Ẹbí | 4 Children |
Awards | Literary Person Of The Year - 2018 |
Website | lolashoneyin.com |
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀
àtúnṣeWọ́n bí Titilola Atinuke Alexandrah Shoneyin sí ìlú Ìbàdàn, èyí tó jẹ́ olú-ìlú ti Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, tó wà ní apá Ìwọ̀-oòrùn ilẹ̀ Nàìjíríà, ní ọdún 1974. Òun ni àbígbẹ̀yìn àwọn ọmọ mẹ́fà àti ọmọbìnrin kan ṣoṣo. Àwọn òbí rẹ̀ Chief Tinuoye Shoneyin àti Mrs. Yetunde Shoneyin (née Okupe), jẹ́ ọmọ-ìlú Remo láti Ìpínlẹ̀ Ògùn.
Ìtàn ayé rẹ̀ àti ìrírí rẹ̀ ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ iṣẹ́ rẹ̀ dálé lórí, ó sọ ọ̀pọ̀lọpọ̀ ohun tó rọ̀ mọ́ fíẹ́ ìyàwó púpọ̀ nínú ìwé alákọ̀ọ́kọ́ rẹ̀; bàbá-ìyá rẹ̀, Abraham Olayinka Okupe (1896-1976) ni olórí Iperu Remo, ó sì ní ìyàwó márùn-ún. Ó gorí oyè ní ọdún 1938, ó sì ṣaláìsí ní ọdún 1976.[11]
Iṣẹ́ rẹ̀
àtúnṣeÌtàn-àròsọ
àtúnṣe- Mayowa and the Masquerades - January 2021[12]
- Nostalgia is an Extreme Sport: An essay from the collection, Of This Our Country - September 2010[13]
- Baba Segi, Ses Épouses, Leurs Secrets October 2016[14]
- The Secret Lives of Baba Segi's Wives, London: Serpent's Tail, May 2010.[15]
- Longlisted for the 2011 Orange Prize,[16] won the 2011 PEN Oakland/Josephine Miles Literary Award[17] and won two Association of Nigerian Authors Awards.[18]
- Translated into seven languages, published in Italian as Prudenti Come Serpenti.
Ìtàn kékeré
àtúnṣe- "Woman in Her Season", Post Express Newspapers, 1996[19]
Ewì
àtúnṣe- So All the Time I was Sitting on an Egg (1998)[20]
- Song of a River Bird, Ovalonion House (Nigeria, 2002)[21]
- For the Love of Flight (2010)[22]
Ìwé àwọn ọmọdé
àtúnṣe- Mayowa and the Masquerade, July 2010, published in the US in 2020[20]
Iṣẹ́ akada ti Lola Shoneyin
àtúnṣe- Abiola, Emmanuel. Negotiating Patriarchal Structures: Polygamy and Female Agency in Lola Shoneyin’s The Secret Lives of Baba Segi’s Wives. Ibadan Journal of English Studies 7 (2018): 497–504.
- Bámgbózé, Gabriel. "Beyond Gender Allegory: A Postcolonial Reading of Lola Shoneyin’s Poetry. Ibadan Journal of English Studies 7 (2018): 155-170.
- Jegede, O. B. Subversive (re) writing and body poetics in Lola Shoneyin’s "So all the time I was sitting on an egg". Ibadan Journal of English Studies 7 (2018): 207–224.
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Lola Shoneyin". BBC World Service - Arts & Culture. BBC. 9 April 2010. Retrieved 2012-12-08.
- ↑ Mary, Aborele (2019-02-26). "Popular Nigerian Literary Icon, Lola Shoneyin, Clocks 45". Welcome To PublicFace Magazine (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2020-08-03. Retrieved 2020-05-30.
- ↑ "An Interview with Lola Shoneyin, African Writing Online [many literatures, one voice]; Issue No. 9". www.african-writing.com. Retrieved 2020-05-30.
- ↑ "Lola Shoneyin". Casafrica (in Èdè Sípáníìṣì). 2021-02-24. Retrieved 2022-10-12.
- ↑ Africa39 list of artists, Hay Festival.
- ↑ "Lola Shoneyin". PEN America (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2015-01-07. Retrieved 2020-05-30.
- ↑ "Lola Shoneyin". David Higham Associates (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-05-30.
- ↑ Muoka, Chidera (26 November 2017). "Lola Shoneyin: Writer, Thinker, Creator". Archived from the original on 24 May 2018. Retrieved 23 May 2018.
- ↑ III, Editorial (2020-04-10). "Ake Arts and Book Festival moves online" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-05-30.
- ↑ Edoro, Ainehi (30 December 2017). "The 2017 Brittle Paper African Literary Person of the Year Is Lola Shoneyin". Brittle Paper. https://brittlepaper.com/2017/12/lola-shoneyin-2017-brittle-paper-person-year/. Retrieved 20 August 2019.
- ↑ Shoneyin, Lola (2010-03-20). "Polygamy? No thanks". The Guardian. Retrieved 2012-12-08.
- ↑ "Mayowa and The Masquerades | Cassava Republic Press" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-05-11. Retrieved 2022-10-12.
- ↑ "Nostalgia is an Extreme Sport: An essay from the collection, Of This Our Country". HarperCollins (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-10-12.
- ↑ "Baba Segi, ses épouses, leurs secrets | Actes Sud". www.actes-sud.fr. Retrieved 2022-10-12.
- ↑ "The Secret Lives of Baba Segi's Wives". Serpent's Tail (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-05-30.
- ↑ Armitstead, Claire (2011-03-16). "Orange prize for fiction 2011: the longlist - gallery" (in en-GB). The Guardian. ISSN 0261-3077. https://www.theguardian.com/books/gallery/2011/mar/16/orange-prize-longlist.
- ↑ "Author". HarperCollins Publishers: World-Leading Book Publisher (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-05-30.
- ↑ "SPLA | Lola Shoneyin". www.spla.pro. Retrieved 2020-05-30.
- ↑ Nigeria, Media (2018-06-05). "Biography Of Lola Shoneyin". Media Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-05-30.
- ↑ 20.0 20.1 "Lola Shoneyin". Africa Book Club (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2012-03-04. Archived from the original on 2020-08-03. Retrieved 2020-05-30.
- ↑ "notes on contributors". www.sentinelpoetry.org.uk. Archived from the original on 2020-08-03. Retrieved 2020-05-30.
- ↑ "An Interview with Lola Shoneyin, African Writing Online [many literatures, one voice]; Issue No. 9". www.african-writing.com. Retrieved 2020-05-30.