Lučka Kajfež Bogataj (tí a bí ní Ọdún 1957) jẹ́ onímọ̀-jìnlẹ̀ ara ìlú Slovenia àti Olúdíje olúborí jojú Nobel ní 2007[1].   .

Lučka Kajfež Bogataj
Ọjọ́ìbíLučka Kajfež Bogataj
28 Oṣù Kẹfà 1957 (1957-06-28) (ọmọ ọdún 66)
Slovenia
Ẹ̀kọ́University of Ljubljana
Iṣẹ́Climatologist

Ìgbésì ayé   àtúnṣe

A bí Bogataj noi Ọdún 1957 . O parí ní ọdún 1980 láti Ljubljana Faculty of Natural Sciences and Technolog àti gbà ìwé-èkọ́ dókítà láti Olùkọ́ ìmọ̀-ẹ̀rọ[2] .

Isé ràle àtúnṣe

O jẹ́ awadi ati alámọ̀dájú ní Unifásítì of Ljubljana . Bogataj jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ tí Ìgbìmọ̀ ìjoba Ìyípadà ní Geneva[3]   .

Àwọn ìdánimọ̀ àtúnṣe

Ní ọdún 2008, Alákòso ìjoba Slovania Lẹ́hínáà, Danilo Türk, fún ní ẹ̀bùn fún àwọn isé takuntakun re[4].    

Àwọn Ìtókasí àtúnṣe