Lubaland
Lubaland jẹ́ igbó kan ní gúúsù Odò Congo níbi tí àwọn ẹ̀yà Luba ń gbé; ni gúúsù ìlà oòrùn orílẹ̀ èdè Democratic Republic of the Congo. Ní ìgbà 1500 CE, àwọn ilẹ̀ Luba parapò láti di ìjọba kan tí Leopold II, ọba Belgium, padà kógun wọ̀ ní 1885, Leopold II sì padà sọ́ di ara àwọn Congo Free State. Lubaland gùn láti odò Lwembe dé ìlà oòrùn Odò Congo, Ilẹ̀ náà kún fún igbó, yàtò sí Upemba Depression.[1]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Luba of Shaba Orientation". Retrieved 2007-07-08.