Mùsíọ́mù ti ìlú Benin

Orilẹ-ede Ile ọnọ ni Ilu Benin

 

Àwòrán mùsíọ́mù ti ìlú Benin

 

Benin City National Museum
benin ilu orilẹ-musiọmu
Map</img>
Ipo Benin City, Nigeria, be ni aarin ilu lori King Square.
Awọn ipoidojuko

Benin city National Museum jẹ́ mùsíọ́mù ní ìlú Benin ní orílẹ̀ èdè nàìjíríà , tí ó wà ní àárín ilu King's Square. Mùsíọ́mù náà ní àwọn ohun-ọ̀ṣọ́ tí ó ṣe pàtàkì sí Ìjọba Benin bíi ìkòkò amọ̀ tàbí àwọn àwòrán tí wọ́n fi amọ̀ yà [[́terracotta],idẹ,àti àwọn irin tí a ti jó pọ̀ . O tún ní àwọn àwòrán àtijọ́ tí ó jẹmọ́ ìgbàanì

The benin city museum wà ní agbègbè ibi kan tí wón ń pè ní Ring Road tí àwọn ara ìlú Benin máa ǹ pè ńi King's Square , ṣùgbọ́n tí Comrade Adams Oshiomhole yí padà sí Ọba Ovonramwen Square lásìkò tí ó wà ní ipò gómìnà ìpínlè náà.

Awọn itọkasi

àtúnṣe