Babatunde Elegbede

Olóṣèlú
(Àtúnjúwe láti M. Elegbede)

Muftau Adégòkè Babátúndé Elégbèdé (c. 1939 - 19 June 1994) òun náà tún ni Túnde Elégbèdé. Ó jẹ́ ọ̀gá ológun ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti Gómìnà Ìpínlẹ̀ Cross River nígbà kan rí.

Muftau Adegoke Babatunde Elegbede
Governor of Cross River State
In office
28 July 1978 – 30 September 1979
AsíwájúPaul Omu
Arọ́pòClement Isong
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbíc. 1939
Aláìsí19 June 1994