Michael Sani Amanesi, tí ìnagige rẹ̀ jẹ́ MC Lively jẹ̀ Òṣèré àti Òṣèfẹ̀ kàn ní orílé èdè Nàìjíríà tí wọ́n bí ní ọjọ́ kefàdínlogun oṣù Kẹjọ, ọdún 1992, tí o jẹ́ ọmọ Agenebode ní ìpìnlẹ̀ Ẹdó ní orílè èdè Nàìjíríà.[1][2][3]

MC Lively
Mc Lively at AMVCA 2020
PseudonymMC Lively
Orúkọ àbísọMichael Sani Amanesi
Ìbí(1992-08-14)Oṣù Kẹjọ 14, 1992
Osun State, Nigeria
Ajẹ́ọmọorílẹ̀-èdèNigerian
Years active2015-present
GenresComedy, Acting

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀ Ìgbé Ayé àti Ètò Ẹ̀kọ́

àtúnṣe

Woọ́n bí MC Lively sí Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun ní ibí tí ó tí ká ìwé Alákọ́bẹ̀rẹ̀ ní ilé ìwé Alákọ́bẹ̀rẹ̀ tí orúko rè ń jẹ́ Ideal àti ilé ìwé sẹ́kọ́ńdírì tí orúko rẹ̀ ń jẹ́ Morèmi.[4] Lẹ́yìn Kíkà ìwé Sẹ́kọ́ndírì, ó tẹ́sìwajú láti lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Fásiti tí Ọbáfẹmi Awólọ́wọ̀ ní ilé ifè, níbi tí ó ti kàwé gboyẹ̀ nínú iṣẹ Òfin (Law), lẹ́yin tí wọn pè sí Nigerian Bar ní ọdún 2016,[4]èyí tí ó kọ sílẹ láti ṣe ìṣe ẹ̀fẹ̀.[5]

Iṣé Kọ́mẹ́dì àti fíìmù

àtúnṣe

Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ Kọ́mẹ́dì ní ọdún 2015, tí o sí jẹ́ mímọ̀ lati ará ẹ̀fẹ̀ kàn tí ó ṣe, tí ó pè ní "Agídí" níbi tí ó tí ṣe nipa àwọn ìṣẹlẹ tí ó ń ṣẹlẹ̀ ní orílé èdè Nàìjíríà.[6]

MC Lively ti ṣiṣẹ́ pẹ̀lú ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn gbajúmò tí wón ń ṣe Ìṣe ẹ̀fẹ̀ bí tirẹ̀, àwọn bí Akpororo, Gosave, àti bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀ lọ.[7] Ó jẹ́ ọ̀kan lára akópa nínú fíìmù tí àkólé rẹ ń jẹ́ "Seven and Half Date" ni ọdún 2028, ti orúkọ rẹ ń jẹ́ James, ẹnìkejì tí ó fẹ́ fẹ́ Bisola.

Óún náà síni Délé nínú eré àgbéléwò kan tí àkólé rẹ ń jẹ́ "Fate of Alakada".[8] and featured in the 2022 film Survivors.[9]

Àwọn àmì ẹ̀yẹ

àtúnṣe

Àwọn mìíràn

àtúnṣe

Ìwé ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Mc Lively: I Didn’t Study Law Because I Wanted to Practice it". Thisdaylive. 2019-06-01. Retrieved 2020-05-01. 
  2. "My mum beat me so much I thought she adopted me –Mc Lively". punchng.com. 2018-12-08. Retrieved 2020-05-01. 
  3. "‘IWas Bounced From Alibaba’s Show In 2017’ – MC Lively". thenet.ng. 2018-07-13. Retrieved 2020-05-01. 
  4. 4.0 4.1 Akintola, Akinbode (2018-08-18). "Been a lawyer has made me a smart comedian-MC Lively". dailytimes.ng. Retrieved 2020-05-01. 
  5. "Everything you should know about the life experience of OAU Lawyer turn Comedian, Mc Lively". insideoau.com. 2020-05-16. Archived from the original on 2021-03-06. Retrieved 2020-12-12. 
  6. "10 Nigerian comedians who became popular on Instagram". pmnewsnigeria.com. 2019-12-11. Retrieved 2020-05-01. 
  7. "Akpororo, MC Lively, Terry G, Small Doctor Others Thrilled Akure Residents at LaffMattazz With Maltina". nigeriacommunicationsweek.com.ng. 2019-06-15. Retrieved 2020-05-02. 
  8. Emma Ossy Isidahomen (2020-01-30). "Fate of Alakada Movie to Have Star-Studded Cast, to Premiere April 10". afrimovieshub.com. Retrieved 2020-05-02. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  9. "Movie Premiere: Mr Macaroni, Broda Shaggi, Mc lively star in ‘Survivor’". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-06-27. Retrieved 2022-07-30.