Maasai
Maasai je eya awon eniyan ni Apailaoorun Afrika. Wọ́n wà ní àdúgbò orílẹ̀ èdè Tanzania àti Kenya, wọ́n sì fẹ́ẹ̀ tó ọ̀kẹ́ mẹ́tàdínlógún ààbọ̀ ní iye. Èdè wọn ni OI Maa wọ́n sì múlé gbe Samburu, Kikuyu, Kamba, Chaga, Meru abbl. Darandaran tààrà ni wọ́n. wọn a sì máa sín ìlẹ̀kẹ̀ gan-an. Ọjọ́ orí ni wọ́n máa fi ń ṣe ìjọba ní ilẹ̀ yìí, obìnrin wọn kìí sìí pẹ́ ní ọkọ ṣùgbọ́n ọkùnrin gbọ́dọ̀ ní owó lọ́wọ́ kí ó tó fẹ́ aya. Ní àsìkò ayẹyẹ pàtàkì, màálù ni wọ́n máa ń fi rúbọ.
A gathering of Maasai women and children in 2006 | ||||||
Àpapọ̀ iye oníbùgbé | ||||||
---|---|---|---|---|---|---|
883,000 | ||||||
Regions with significant populations | ||||||
| ||||||
Èdè | ||||||
Maa (ɔl Maa) | ||||||
Ẹ̀sìn | ||||||
Monotheism | ||||||
Ẹ̀yà abínibí bíbátan | ||||||
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |