Macy Gray

Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America

Macy Gray (oruko abiso Natalie McIntyre, 6 September 1967 ni Canton, Ohio, USA)[1][2] je akorin-adaorin R&B ati soul, atokun awo-orin, ati osere ara Amerika to gba Ebun Grammy, o gbajumo fun ohun hiha re ati iru ikorin to jo bi Billie Holiday ati Betty Davis.

Macy Gray
Macy Gray ni 2008
Macy Gray ni 2008
Background information
Orúkọ àbísọNatalie Renee McIntyre
Ọjọ́ìbíOṣù Kẹ̀sán 6, 1967 (1967-09-06) (ọmọ ọdún 56)
Canton, Ohio, United States
Irú orinR&B, soul, neo soul, hip hop
Occupation(s)Singer-songwriter, record producer, actress
Years active1990–present
LabelsAtlantic (1994-1996)
Epic (1998-2004)
will.i.am / Geffen (2006-2008)
Concord (2009-2011)
429 (2011-)
Associated actsBobby Brown, Natalie Cole, Velvet Revolver, Pharoahe Monch, The Black Eyed Peas
Websitemacygray.com


Itokasi àtúnṣe

  1. "It's a Macy, Macy world". The Guardian. 18 November 2001. http://www.guardian.co.uk/theobserver/2001/nov/18/life1.lifemagazine5. Retrieved 22 January 2012. 
  2. Bio at All Music.com