Malaika Uwamahoro
Malaika Uwamahoro (bíi ni ọdún 1990) jẹ́ òṣèré, akéwì, olórin àti ajìjàgbara lórílẹ̀ èdè Rwanda.[1][2][3]
Malaika Uwamahoro | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Malaika Uwamahoro 1990 Rwanda |
Iṣẹ́ | |
Gbajúmọ̀ fún |
|
Ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀
àtúnṣeWọ́n bí Malaika sí Rwanda ní ọdún 1990. Nítorí ìṣẹ̀lẹ̀ tí ó wáyé ní ọdún 1994, òun àti ìyá rẹ sá kúrò ní Rwanda lọ sí Uganda.[4] Ó gboyè nínú ìmò eré orí ìtàgé láti ilé ẹ̀kọ́ gíga tí Fordham University.[5]
Iṣẹ́
àtúnṣeÓ kópa nínú eré Loveless Generation èyí tí Tomas Petkovski gbé kalẹ̀ ní ọdún 2018[6]. Ní ọdún náà, ó ṣe bí Princess nínú eré Yankee Hustle.[7] Ní ọdún 2019, ó farahàn nínú eré Our Lady of the Nile.[8][9][10][11][12] Ipa tí ó kó nínú eré Miracle in Rwanda ni wọ́n fi yàán fún àmì ẹ̀yẹ Best Solo Performance ní VIV Award ni ọdún 2019.[13][14] Ó wá nínú orin Stickin' 2 You èyí tí Mucyo kọ.[15] Ó wá lára àwọn tó dárà níbi ayẹyẹ DanceAfrica event ní ọdún 2019.[16] Ní ọdún 2020, ó jẹ́ ìkan lára àwọn obìnrin tí wọ́n pè láti sọ̀rọ̀ níbi ayẹyẹ Forbes Woman Africa 2020 Leading Women Summit tí wọ́n ṣe ni South Áfríkà.[17][18]
Àwọn Ìtọ́kàsi
àtúnṣe- ↑ Armstrong, Linda (April 18, 2019). "‘Miracle in Rwanda’ shows the power of faith, love, forgiveness". New York: Amsterdam News. Retrieved November 25, 2020.
- ↑ Methil, Renuka (May 3, 2020). "‘Our Home Became The Film Set, Blankets Became Props, Windows Became Locations’". Forbes Africa. Retrieved November 24, 2020.
- ↑ Methil, Renuka (May 3, 2020). "‘Our Home Became The Film Set, Blankets Became Props, Windows Became Locations’". Forbes Africa. Retrieved November 24, 2020.
- ↑ Opobo, Moses (April 12, 2017). "Kwibuka23: Uwamahoro’s appeal to world leaders". The New Times. Retrieved November 25, 2020.
- ↑ "'Learn the lessons of Rwanda,' says UN chief, calling for a future of tolerance, human rights for all". UN News. April 7, 2017. Retrieved November 25, 2020.
- ↑ "LoveLess Generation (2018)". IMDb. Retrieved November 24, 2020.
- ↑ "Yankee Hustle (2018– )". IMDb. Retrieved November 24, 2020.
- ↑ "Our Lady of the Nile (2019)". IMDb. Retrieved November 24, 2020.
- ↑ Santiago, Luiz (October 31, 2020). "CRITICISM | OUR LADY OF THE NILE". Plano Crítico. Retrieved November 25, 2020.
- ↑ Keizer, Mark (September 5, 2019). "Film Review: ‘Our Lady of the Nile’". Variety. Retrieved November 25, 2020.
- ↑ Lemercier, Fabien (September 6, 2019). "TORONTO 2019 Contemporary World Cinema | Review: Our Lady of the Nile". Cineuropa. Retrieved November 25, 2020.
- ↑ "Drive In to the Opening Night Films from Method Fest". Broadway World. August 18, 2020. Retrieved November 25, 2020.
- ↑ Hetrick, Adam (February 12, 2019). "Miracle in Rwanda Will Arrive Off-Broadway This Spring". Playbill. Retrieved November 25, 2020.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ Meyer, Dan (October 15, 2019). "The Secret Life of Bees, Much Ado About Nothing Lead 2019 AUDELCO’s VIV Award Nominations MEYER". Playbill. Retrieved November 25, 2020.
- ↑ Kanaka, Dennis (February 19, 2020). "Kigali Creatives: The Backstory to “Stickin’ 2 You”". The New Times. Retrieved November 25, 2020.
- ↑ Chavan, Manali (May 23, 2019). "Weekend Art Events: May 24-26 (DanceAfrica 2019, Coney Island History Project, Memorial Day Concert & More)". Bklykner. Retrieved November 25, 2020.
- ↑ "Women Summit announces its speaker line-up". Media Unit. March 2, 2020. Retrieved November 25, 2020.
- ↑ Iribagiza, Glory (February 13, 2020). "Uwamahoro to speak at Forbes 2020 women summit". The New Times. Retrieved November 24, 2020.