Mamady Doumbouya (N'Ko: ߡߊ߬ߡߊߘߌ߫ ߘߎ߲ߓߎߦߊ߫, tí a bí ọjọ́ kẹrin oṣù kẹta ọdún 1980) jẹ́ ológun ọmọ orílẹ̀ ède Guinea, òun ni Ààrẹ orílẹ̀ ède Guinea láti ọjọ́ Kínní oṣù Kẹ̀wá ọdún 2021. Doumbouya dárí ìdìtẹ̀ gba ìjọba tí ó ṣẹlẹ̀ ní ọjọ́ Kàrún oṣù kẹsàn-án 2021 láti gba ìjọba lọ́wọ́ Alpha Condé. Ní ọjọ́ tí ìdìtẹ̀ gba ìjọba náà ṣẹlẹ̀, Doumbouya kéde lórí ẹ̀rọ aṣọ̀rọ̀-má-gbèsì pé ìjọba ti tú ìjọba tẹ́lẹ̀ ká, ó tún kéde pé òfin ìlú náà ó dúró mọ́. NÍ ọjọ́ Kínní oṣù kẹwàá 2021, á kéde Doumbouya gẹ́gẹ́ bí Ààrẹ.[1]


Mamady Doumbouya
ߡߊ߬ߡߊߘߌ߫ ߘߎ߲ߓߎߦߊ߫
Doumbouya in 2022
President of Guinea
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
1 October 2021
Alákóso ÀgbàMohamed Béavogui
Bernard Goumou
Bah Oury
AsíwájúAlpha Condé
Chairman of the National Committee of Reconciliation and Development
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
5 September 2021
AsíwájúOffice established
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí4 Oṣù Kẹta 1980 (1980-03-04) (ọmọ ọdún 44)
Kankan, Guinea
(Àwọn) olólùfẹ́Lauriane Darboux
Àwọn ọmọ4
Military service
Allegiance France (formerly)
 Guinea
Branch/service French Foreign Legion (formerly)
 Adigun Guinea
Rank Colonel

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Guinea swears in coup leader Mamady Doumbouya as interim president". CNN. Reuters. October 2021. Archived from the original on 25 October 2021. Retrieved 10 August 2023.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)