Mamman Daura (tí á bí ní ọdún 1939) jẹ́ olóòtù ìròyìn ti Nàìjíríà tí ó ṣé àtúnkọ, tí ó padà ṣe ìṣàkóso Nàìjíríà tuntun láti ọdún 1969 di 1975. Ó jẹ́ ẹ̀gbọ́n sí Ààrẹ Muhammadu Buhari[1] àti ọ̀kan gbòógì ọmọ ẹgbẹ́ Kaduna Mafia, ẹgbẹ́ aláìmúnisìn oníṣòwò, òṣìṣẹ́ ìlú, ọ̀jọ̀gbọ́n àti olórí ológún láti ilẹ̀-Àríwá Náìjíríà.[2][3][4]

Mamman Daura
Àdàkọ:Post-nominals
Ọjọ́ìbí1939 (ọmọ ọdún 84–85)
Orílẹ̀-èdèNigerian
Iléẹ̀kọ́ gígaTrinity College Dublin
Iṣẹ́Newspaper editor
Gbajúmọ̀ fúnLeading Kaduna Mafia

Ìgbésí ayé rẹ̀

àtúnṣe

A bí Mamman Daura ní Daura, Ílè Aríwà, British Nigeria ní ọdún 1939,[5] bàbá rẹ̀ Alhaji Dauda Daura dì oyé Durbin Daura tí Daura Emirate;[6] ó sì jẹ́ ẹ̀gbọ́n Muhammadu Buhari.[7] Ó kẹ́ẹ̀kọ́ ní Daura Elementary School, Katsina Middle School kí ó tó lọ sí Provincial Secondary School, Okene. Ní ọdún 1956, nígbà tó pé ọmọ ọdún mẹ́tàdínlógún, ó bẹ̀rẹ̀ síí ṣíṣẹ́ pẹ̀lú Daura Native Authority fún ọdún díẹ̀ kí ó tó dáràpọ̀ mọ́ Nigerian Broadcasting Corporation. Ó jẹ́ ọ̀kan lára ọmọ ilẹ̀-Àríwá mẹ́fà tí Sir Ahmadu Bello yàn láti kẹ́kọ̀ọ́ ní England

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. PADEN, JOHN N (2016) (in en). MUHAMMADU BUHARI;THE CHALLENGES OF LEADERSHIP IN NIGERIA. ROARING FORTIES PRESS. p. 7. ISBN 978-1938901683. 
  2. Journalist, Naija (27 October 2019). "Mamman Daura: Facts about President Muhammadu Buhari's 'powerful nephew'". Medium (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 7 May 2020. 
  3. Babah, Chinedu (10 November 2019). "DAURA,Mamman". Biographical Legacy and Research Foundation (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 30 May 2020. 
  4. Daura, Fatima (9 November 2019). "Malam Mamman Daura: Tribute to Baba at 80!". Daily Trust (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 15 December 2019. Retrieved 30 May 2020. 
  5. Baiye, Clem (14 November 2019). "Mamman Daura at 80: A tribute". The Nation. 
  6. "A tribute to Mamman Daura at 80". TheCable (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 9 November 2019. Retrieved 9 August 2020. 
  7. N. Paden, John (2016). Muhammadu Buhari: The Challenges of Leadership in Nigeria. pp. 7.