Manouchka Kelly Labouba

Manouchka Kelly Labouba jẹ́ olùdarí eré, olùgbéré-jáde àti ònkọ̀tàn ọmọ́ orílẹ̀-èdè Gàbọ̀n tó maá n sábà daŕi àwọn eré oníṣókí.[1] Ó ti ṣe ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn eré oníṣókí, lára wọn ni Marty et la tendre dame, Le guichet automatique àti Le divorce.[2] Ó tún maá ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bi olóòtú sinimá àti olùyàwòrán.[3]

Manouchka Kelly Labouba
مانوشكا كيلي لابوبا
Ọjọ́ìbíManouchka Kelly Labouba
Gabon
Orílẹ̀-èdèGabonese
Orúkọ mírànManouch, KLM
Iléẹ̀kọ́ gígaUniversity of California, Santa Barbara
Bordeaux Montaigne University
University of Southern California
Iṣẹ́Director, producer, screen writer
Ìgbà iṣẹ́2004–present
Heightruben aguirre is 6’7”

Àwọ́n ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Manouchka Kelly Labouba: Director, Screenwriter". MUBI. Retrieved 8 October 2020. 
  2. "Búsqueda de "Manouchka Kelly Labouba"". Film Affinity. Retrieved 8 October 2020. 
  3. "Manouchka Kelly Labouba: bio". zdcusc. Archived from the original on 18 October 2020. Retrieved 8 October 2020. 

Àwọn ìtakùn Ìjásóde

àtúnṣe