Married but Living Single

Married but Living Single jẹ́ fíìmù ajẹmọ́fẹ̀ẹ́ ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó jáde ní ọdún 2012, èyí tí Tunde Olaoye darí, tí ó sì ṣàfihàn àwọn akópa bí i Funke Akindele, Joseph Benjamin, Joke Silva, Tina Mba, Kiki Omeili àti Femi Brainard.[3][4][5][6][7] Ìwé tí Pastor Femi Faseru ti KICC Lagos kọ ló dúró gẹ́gẹ́ bí i ìwúnilórí tí wọ́n fi gbé fíìmù yìí jáde.[8] Fíìmù náà sọ ìtàn Kate (Funke Akindele), tó jẹ́ obìnrin atẹpámọ́ṣẹ́ tó sì tún jẹ́ ìyàwó arákùmrin oníṣòwò kan, ìyẹn Mike (Joseph Benjamin). Mike dùbúlẹ̀ àìsàn, pẹ̀lú àrùn jẹjẹrẹ ti ọ̀nàfun; Kate sì ní láti yàn, yálà kó dúró ti ọkọ̀ rẹ̀ ní ilé-ìwòsàn láti máa mójútó o, tàbí kó padà sí ẹnu iṣẹ́. Àsìkò yìí tún wá jẹ́ ìgbà tí wọ́n ṣiṣẹ́ láti gba iṣẹ́ ńlá kan tó sì ní owó iyebíye lórí.

Married but Living Single
Fáìlì:Married but Living Single poster.jpg
Theatrical release poster
AdaríTunde Olaoye
Olùgbékalẹ̀Kalejaiye Paul
Àwọn òṣèré
OrinSanjo Adegoke
Ìyàwòrán sinimáMoruf Fadairo
OlóòtúShola Ayorinde
Seyi-Ola Emmanuel
Ilé-iṣẹ́ fíìmùIndelible Mark Media
Déètì àgbéjáde
  • 3 Oṣù Kẹfà 2012 (2012-06-03)
Orílẹ̀-èdèNigeria
ÈdèEnglish
Ìnáwó₦30 million (est)[1]
Owó àrígbàwọlé₦9,900,000[2]

Àwọn akópa

àtúnṣe

Àgbéjáde

àtúnṣe

Wọ́n ṣe àgbéjáde ìpolówó fíìmù yìí ní 20 February 2012, pẹ̀lú àwọn àwòrán lóríṣiríṣi.[9][10][11] Ìṣàfihàn àkọ́kọ́ rẹ̀ wáyé ní Silverbird Galleria, ní Èkó ní ọjọ́ kẹta oṣù kẹfà ọdún 2012;[12][13][14] èyí tí igbá kejì Gómínà ìpínlẹ̀ Èkó farahàn níbẹ̀, ìyẹn Adejoke Orelope-Adefulire.[15] Gbọ̀ngàn márààrún ti sinimá yìí kún dẹ́múdẹ́mú.[15] Lẹ́yìn náà ni wọ́n wá gbe síta fún wíwò ní àwọn sinimá yòókù ní ọjọ́ karùn-ún oṣù kẹfà ọdún 2012.[16][17] Bákan náà ni wọ́n gbe síta fún wíwò ní Scotland.[18]

Àmì-ẹ̀yẹ

àtúnṣe

Wọ́n yan fíìmù yìí fún ìsọ̀rí márùn-ún ní 2012 Best of Nollywood Awards, lára wọn ni "Fíìmù tó dára jù lọ", "Olùdarí tó dára jù lọ", "Òṣèrébìnrin tó dára jù lọ" fún Akindele, àti "Òṣèrẹ́mọdé tó dára jù lọ" fún Deola Faseyi; Benjamin gba àmì-ẹ̀yẹ fún "Ẹ̀dá-ìtàn, òṣèrékùnrin tó dára jù lọ". Wọ́n tún yan Faseyi lẹ́ǹkan si ní 2013 Nollywood Movies Awards fún "Òṣèrémọdé tó dára jù lọ".

Àwọn àmì-ẹ̀yẹ
Àmì-ẹ̀yẹ Ìsọ̀rí Olùgbà Èsì
Best of Nollywood Magazine
2012 Best of Nollywood Awards[19]
Movie of the Year Tunde Laoye Wọ́n pèé
Director of the Year Tunde Laoye Wọ́n pèé
Best Lead Actress in an English Film Funke Akindele Wọ́n pèé
Best Lead Actor in an English Film Joseph Benjamin Gbàá
Child actress of the year Deola Faseyi Wọ́n pèé
Nollywood Movies Network
2013 Nollywood Movies Awards[20]
Best Child Actor Adeola Faseyi Wọ́n pèé
17th African Film Awards[21] Best Actress in a Supporting Role (English Film) Kiki Omeili Gbàá

Fíìmù àgbéléwò

àtúnṣe

Wọ́n ṣe ìṣàfihàn àkọ́kọ́ rẹ̀ lórí VOD ní ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹrin ọdún 2013 lórí Distrify.[22] Wọ́n sì ṣàgbéjáde rẹ̀ sí orí DVD ní ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹjọ ọdún 2013.[23]

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "10 HIGHEST GROSSING NIGERIAN MOVIES". Encomium. Encomium Magazine. 17 September 2013. Retrieved 20 September 2014. 
  2. "Funke Akindele: The Richest Nollywood Actress". Ride Natty Ride. Archived from the original on 12 February 2015. Retrieved 12 February 2015. 
  3. "Joke Silva, Joseph Benjamin and Funke Akindele in Married But Living Single". ONTV. OnTV. 8 March 2012. Archived from the original on 23 September 2014. Retrieved 20 September 2014.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  4. Moses, Chika (28 February 2012). "Funke Akindele & Joseph Benjamin are "Married but Living Single"… photos and video!". Pilot Africa. Retrieved 20 September 2014. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  5. "Review: Married but Living Single". Pamela Stitch. Archived from the original on 7 June 2013. Retrieved 22 September 2014. 
  6. "Funke Akindele gets married in "Married but living single"". Channels. Channels Television. 29 February 2012. Retrieved 22 September 2014. 
  7. Nwakwo, Uzoma (22 October 2012). "Nigeria Movie Married But Living Single". Nigeria Business Pages. Retrieved 22 September 2014. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  8. "'Married But Living Single' Premieres June 3". Nollywood Mindspace. Nollywood By Mndspace. 27 May 2012. Retrieved 20 September 2014. 
  9. Okiche, Wilfred. "Movie trailer: Funke Akindele and Joseph Benjamin Tango in 'Married but Living Single'". YNaija. YNaija!. Retrieved 20 September 2014. 
  10. Aiki, Damilare (27 April 2012). "Executive Producer of "Married but Living Single" Speaks to Toolz on his Upcoming Movie". Bella Naija. bellanaija.com. Retrieved 22 September 2014. 
  11. Aiki, Damilare (28 February 2012). "Funke Akindele & Joseph Benjamin are "Married" – in new movie – "Married but Living Single" starring Joke Silva, Tina Mba, Femi Brainard & More – Photos & Trailer". Bella Naija. bellanaija.com. Retrieved 23 September 2014. 
  12. "Married But Living Single To Premiere On Sunday". PM News Nigeria. 21 May 2012. Retrieved 20 September 2014. 
  13. Erin (26 September 2012). "'Married But Living Single' Movie Premiere Photos". African Seer. Archived from the original on 13 September 2014. Retrieved 20 September 2014. 
  14. "Married but Living Single - African movie". Fienipa. 19 September 2014. Retrieved 22 September 2014. 
  15. 15.0 15.1 Lasisi, Akeem (6 July 2012). "Married but Living Single's journey to cinema". Punch Newspaper. Punch NG. Archived from the original on 6 October 2014. Retrieved 20 September 2014. 
  16. "The London Premiere of 'MARRIED BUT LIVING SINGLE' the Movie". Naija Life. 26 September 2012. Archived from the original on 23 September 2014. Retrieved 20 September 2014.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  17. Odunowo, Bunmi (1 March 2012). "Funke Akindele Marries Joseph Benjamin in new movie "Married but Living Single"". Archived from the original on 6 October 2014. Retrieved 23 September 2014. 
  18. "MARRIED BUT LIVING SINGLE MOVIE SCREENING IN ABERDEEN". Trendy PR. Retrieved 23 September 2014. 
  19. "Best of Nollywood Awards list of Nominees". Nollywood Mindspace. Nollywood by Mindspace. 9 September 2012. Archived from the original on 15 October 2014. Retrieved 23 September 2014.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  20. "OC Ukeje, Gabriel Afolayan, Funke Akindele, Imeh Bishop Udoh lead Nominees for Nollywood Movies Awards". Nigeria Entertainment Today. The NET NG. September 2013. Archived from the original on 26 March 2014. Retrieved 23 September 2014.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  21. Opurum, Nkechi (23 October 2012). "Tonto Dikeh, Kiki Omeili Win Afro-Hollywood Awards". Daily Times Nigeria (Lagos, Nigeria). Archived from the original on 10 November 2012. https://web.archive.org/web/20121110085400/http://dailytimes.com.ng/article/tonto-dikeh-kiki-omeili-win-afro-hollywood-awards. Retrieved 1 November 2012. 
  22. "MARRIED BUT LIVING SINGLE RELEASED ONLINE TODAY - DISTRIFY.COM". Nollywood Uncut. 26 April 2013. Archived from the original on 4 June 2013. Retrieved 23 September 2014.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  23. "Married but living single hits Nigerian today". The Sun Newspaper. SunNewsOnline. 29 August 2013. Retrieved 22 September 2014.