Mary Ekpere-Eta
Mary Ekpere-Eta jẹ́ agbẹjọro ati ajafitafita ọmọ Nàìjíríà. Ó jẹ́ Oludari Gbogbogbo ti National Centre for Women Development (NCWD) ní Abuja.
Igbesi aye
àtúnṣeMary Eta jẹ́ agbẹjọro, àti elegbe tí Chartered Institute of Taxation ní Nàìjíríà Odun 2012 ló tun fé láti di Gómìnà ìpínlẹ̀ Cross River. Árabinrin náà jẹ aṣoju fun awọn obinrin South-South ninu igbimọ alabojuto ti Gbogbo All Progressive Congress (APC).[1]
Aare Buhari yan Ekpere-Eta gẹgẹbi Oludari Gbogbogbo ti NCWD ni Oṣu Kẹrin ọdun 2017.[2][1]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 Nkechi China Onyele (12 September 2017). "Women must never settle for inferior positions – Eta, DG, National Centre for Women Development]". The Sun (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì).
- ↑ Omeiza Ajayi (13 April 2017). "Buhari sacks Heads of CPC, PENCOM, 21 Others". Vanguard (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì).