Lois Maureen Stapleton jẹ́ Òṣèré sinimá ágbéléwò tó gba Ámìn Ẹ̀yẹ Akádẹmì gẹ́gẹ́ bí òṣèrébìnrin aṣègbè fún olú ẹ̀dá ìtàn tó dára jù lọ.

Maureen Stapleton
Ọjọ́ìbíLois Maureen Stapleton
(1925-06-21)Oṣù Kẹfà 21, 1925
Troy, New York, U.S.
AláìsíMarch 13, 2006(2006-03-13) (ọmọ ọdún 80)
Lenox, Massachusetts, U.S.
Iṣẹ́Actress
Ìgbà iṣẹ́1946–2003
Olólùfẹ́
  • Max Allentuck
    (m. 1949; div. 1959)
  • David Rayfiel
    (m. 1963; div. 1966)
Àwọn ọmọ2

Ìbẹ́rẹ́ ayé àti ètò ékọ́ rẹ̀

àtúnṣe

Wọ́n bí Stapleton sí Troy, New York,tí awọn òbí rẹ̀ jẹ́ John P. Stapleton ati Irene (née Walsh).