Maurice Kouandété je ara orile-ede Benin ati Aare ile Benin tele.