Mavis Adjei
Mavis Adjei jẹ́ oṣ̀eré orílẹ̀ ède Ghana kan tí ó ń gbé ní orílẹ̀ ède Netherlands.
Ìgbésí ayé ìbẹ̀rẹ̀ àti ẹ̀kọ́
àtúnṣeAdjei jẹ́ ọmọ ìlú Akwatia ní Ilà-oòrùn Ẹkùn ti Ghana. Ó lọ ilé ẹ̀kọ́ girama Swedru Secondary School ní àárín <a href="./Agbegbe Ila-oorun, Ghana" rel="mw:WikiLink" data-linkid="10" data-cx="{"adapted":false,"sourceTitle":{"title":"Eastern Region (Ghana)","thumbnail":{"source":"https://upload.wikimedia.org/wikipedia/commons/thumb/5/5e/Umbrella_Rock_at_Boti_Falls.jpg/80px-Umbrella_Rock_at_Boti_Falls.jpg","width":80,"height":53},"description":"Region[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́] of Ghana","pageprops":{"wikibase_item":"Q405670"},"pagelanguage":"en"},"targetFrom":"mt"}" class="mw-redirect cx-link" id="mwCw" title="Agbegbe Ila-oorun, Ghana">Ẹkùn</a> Ghana láti ọdún1994 sí ọdún 1996.
Iṣẹ́ tó yàn láàyò
àtúnṣePẹ̀lú àwọn eré oníse tí ó lé ní márùndínlọ́gbọ̀n tí ó ti gba oríyìn, àwọn ipa tí ó kó nínú ere onise ni "Amsterdam Diary, Love & Politics, Church Money, Obaa pa, Salãm àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn mìíràn. Ó tún kópa nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ eré oníse kéékèèké ní Ghana.
Ìgbésí ayé rẹ̀
àtúnṣeAdjei n ́gbé ní orílẹ̀ èdè Netherlands pẹ̀lú àwọn ọmọ rẹ̀: ọmọbìnrin méjì, Tyra àti Kayla, àti ọmọkùnrin rẹ̀, Kieran.
Ìtọ́kasí