Baálẹ̀

(Àtúnjúwe láti Mayor)

Baálẹ̀ ni oruko oye ti Yoruba n pe olori abúlé tabi agbegbe kan. Bakanna Baale (mayor) ni olori ijoba ilu tabi ijoba ibile kan. Awon omo-ilu ni won maa no je oye Baale. Won maa n je asoju Oba alade ni awon ilu kerejekereje ti o back wa labe akoso iru Oba bee. Oba alade ni won maa n fi Baale joye nile Yoruba[1]


ItokasiÀtúnṣe