Chiagozie Fred Nwonwu ẹni tí ó kọ̀wé lábẹ́ gègé orúkọ Mazi Nwonwu jẹ́ òǹkọ̀wé ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, alábòójútó àti ayẹ̀ròyìn wò. Ó pẹ̀lú àwọn olùdásílẹ̀ àti alákòóso ayẹ̀ròyìn wò ti Omenana Magazine.[1][2][3][4] Ní ọdún 2017, wọ́n to orúkọ rẹ̀ wà lára ọ̀kan àwọn ènìyàn alágbára jàǹkàn-jàǹkàn ní agbègbè ìròyìn kíkọ pẹ̀lúpẹ̀lú Stephanie Busari and Fisayo Soyombo látọwọ́ YNaija.[5][6]

  1. "Mazi Nwonwu". Omenana Magazine. Retrieved August 26, 2021. 
  2. "BBC Radio 4 - Writing a New Nigeria - Meet the authors". BBC. Retrieved August 26, 2021. 
  3. Geoff, Ryman (May 31, 2018). "Mazi Chiagozie Nwonwu". Strange Horizons. Issue: 100 African Writers of SFF-Part Nine: The Ake Festival. Retrieved August 26, 2021. 
  4. "POET OF NO COUNTRY (by Eriata Oribhabor Poetry Prize Judge Mazi Chiagozie F Nwonwu)". WRR. December 20, 2012. Retrieved August 26, 2021. 
  5. YNaija (January 3, 2018). "#YNaijaPowerList2017: Stephanie Busari, Uche Pedro, Fisayo Soyombo… See the most powerful young persons in the media space » YNaija". YNaija. Retrieved August 26, 2021. 
  6. "Stephanie Busari, Morayo Afolabi-Brown, Kemi Adetiba named in #YNaijaPowerlist2017 for "Most Powerful Young People in Media"". OloriSuperGal. September 8, 2017. Retrieved August 26, 2021. 
Mazi Nwonwu
Ọjọ́ ìbíChiagozie Fred Nwonwu
Nkwe, Enugu, Nigeria
Pen nameMazi Nwonwu
Iṣẹ́Writer, Journalist
ÈdèEnglish, Igbo
Ọmọ orílẹ̀-èdèNigerian
CitizenshipNigeria
Ẹ̀kọ́Ilé-ẹ̀kọ́ ìkọ́ni ti ìjọba, ní ìpínlẹ̀ Kaduna
Alma materNnamdi Azikiwe University
GenresScience fiction, fantasy