Mercedes McCambridge
Mercedes McCambridge ni à bini ọjọ kẹfadinlógun óṣu March, ọdun 1916 ti ó si ku ni ọdun 2004 jẹ óṣèrè lóbinrin ti Radio, Stage, Film ati Television ilẹ America to gba Ebun Akademi bi Obinrin osere keji to dara ju lo. [1][2]
Mercedes McCambridge | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Carlotta Mercedes Agnes McCambridge Oṣù Kẹta 16, 1916 Joliet, Illinois |
Aláìsí | March 2, 2004 La Jolla, California | (ọmọ ọdún 87)
Iléẹ̀kọ́ gíga | Mundelein College |
Iṣẹ́ | Actress |
Ìgbà iṣẹ́ | 1930s–2004 |
Olólùfẹ́ |
|
Àwọn ọmọ | 1 |
Igbèsi Àyè Àràbírin naa
àtúnṣeMcCambridge ni a bini Jolliet, Illinois fun Marie ati John Patrick (Agbẹ). Awọn óbi óṣèrè lóbinrin naa jẹ ijọ catholic ati Iran Irish-American. Óṣèrè lobinrin naa bẹrẹ irin ajo iṣẹ rẹ gẹgẹ̀bi óṣèrè ti radio ati ṣiṣè èrè ni Broadway ni ọdun 1930s[3].
McCambridge fẹ ọkọ rẹ akọkọ William Fifield ni ọdun 1939 ti wọn si bi ọmọ ọkunrin John Lawrence Fifield ni óṣu December, ọdun 1941. Tọkọ taya naa pinya ni ọdun 1946 leyin igbeyawó ọdun mèjè. Ni ọdun 1950, Óṣèrè lobinrin naa fẹ óṣèrè/producer/oludari Fletcher Markle. Tọkọ taya naa pinya ni ọdun 1962 lẹyin Igbeyawó ọdun mèjila. McCambridge ku ni óṣu March ni ọdun 2004 ni La Jolla, San Diego, California[4][5].
Ẹkọ
àtúnṣeMercedes jade lati collegi ti Mundelein ni ilù Chicago[6][7].
Ipà Óṣèrè lóbinrin ninu èrè àgbèlèwò
àtúnṣeỌdun | Akọle | Ipa Óṣèrè lóbinrin ninu èré àgbèlèwò | Notes |
---|---|---|---|
1949 | All the King's Men | Sadie Burke | Golden Globe Award for Best Supporting Actress |
1951 | Inside Straight | Ada Stritch | |
1951 | The Scarf | Connie Carter | |
1951 | Lightning Strikes Twice | Liza McStringer | |
1951 | Screen Snapshots: Hollywood Awards | Herself | short subject |
1954 | Johnny Guitar | Emma Small | |
1956 | Giant | Luz Benedict | Nominated – Academy Award for Best Supporting Actress |
1957 | A Farewell to Arms | Miss Van Campen | |
1957 | Wagon Train | Emily Rossiter | Episode: "The Emily Rossiter Story" |
1958 | Touch of Evil | Gang leader | Uncredited |
1959 | Suddenly, Last Summer | Mrs. Grace Holly | |
1960 | Rawhide | Mrs Martha Mushgrove | Episode: "Incident of the Captive" |
1960 | Rawhide | Mrs Miller | Episode: "Incident of the Curious Street" |
1959 | Riverboat | Jessie Quinn | Episode: "Jessie Quinn" |
1960 | Cimarron | Mrs. Sarah Wyatt | |
1961 | Angel Baby | Sarah Strand | |
1962 | Rawhide | Ada Randolph | Episode: "The Greedy Town" |
1962 | Bonanza | Deborah Banning | Episode: "The Lady from Baltimore" |
1963 | The Dakotas | Jay French | Episode: "Trouble at French Creek" |
1965 | Run Home Slow | Nell Hagen | |
1965 | Rawhide | Ma Gufler | Episode: "Hostage for Hanging" |
1966 | Lost in Space | Sybilla | Episode: "The Space Croppers" |
1968 | The Counterfeit Killer | Frances | |
1968 | Bewitched | Carlotta | Episode: "Darrin Gone! and Forgotten?" |
1969 | 99 Women | Thelma Diaz | |
1969 | Justine | Madame Dusbois | |
1970 | Bonanza | Matilda Curtis | Episode: "The Law and Billy Burgess" |
1971 | Gunsmoke | Rubilee Mather | Episode: "The Lost" |
1971 | The Last Generation | (archive footage) | |
1973 | The President's Plane Is Missing | Hester Madigan | TV movie |
1973 | Sixteen | Ma Irtley | |
1973 | The Exorcist | Pazuzu | Voice |
1975 | Who Is the Black Dahlia? | Grandmother | TV movie |
1977 | Thieves | Street Lady | |
1978 | Charlie's Angels | Norma | Episode: "Angels in Springtime" |
1978 | Flying High | Claire | Episode: "In the Still of the Night" |
1979 | The Concorde ... Airport '79 | Nelli | |
1979 | The Sacketts | Ma Sackett | TV movie |
1981 | Magnum, P.I. | Agatha Kimball | Episode: "Don't Say Goodbye" |
1983 | Echoes | Lillian Gerben | |
1986 | Amazing Stories | Miss Lestrange | Voice, Episode: "Family Dog" |
1988 | Cagney & Lacey | Sister Elizabeth | Episode: "Land of the Free" |
2018 | The Other Side of the Wind | Maggie | Previously unreleased (final film role) |
Ami Ẹyẹ ati Idànilọla
àtúnṣeLatari ipa óṣèrè lóbinrin naa ni television ati aworan Motion ti Industry ni a fun ni irawọ mèji lori Hollywood Walk of Fame[8][9].
Awon Itokasi
àtúnṣe- ↑ Bergan, Ronald (2004-03-19). "Obituary: Mercedes McCambridge". the Guardian. Retrieved 2018-05-20.
- ↑ "Mercedes McCambridge". TVGuide.com. 2018-05-15. Retrieved 2018-05-20.
- ↑ https://usatoday30.usatoday.com/life/people/2004-03-17-mercedes-mccambridge_x.htm
- ↑ https://www.aymag.com/murder-mystery-the-mask-of-mercy/
- ↑ https://www.nytimes.com/2004/03/18/arts/mercedes-mccambridge-87-actress-known-for-strong-roles.html
- ↑ https://snaccooperative.org/ark:/99166/w6r21bv2
- ↑ http://libapps.luc.edu/digitalexhibits/s/voices-from-mundelein/item/275#:~:text=Mercedes%20McCambridge%20was%20born%20in,with%20NBC%20in%20the%201930s.
- ↑ https://walkoffame.com/mercedes-mccambridge/
- ↑ https://projects.latimes.com/hollywood/star-walk/mercedes-mccambridge/index.html