Michael Babatunde Olátúnjí
Michael Babatunde Olatunji (April 7, 1927 – April 6, 2003) oje onílù Nàìjíríà, olukọni, alapon nínú awujọ, ati Olorin .[1]
Babatunde Olatunji | |
---|---|
Orúkọ àbísọ | Michael Babatunde Olatunji |
Ọjọ́ìbí | Ajido, Lagos State, British Nigeria | Oṣù Kẹrin 7, 1927
Aláìsí | April 6, 2003 Salinas, California | (ọmọ ọdún 75)
Irú orin | Yoruba music, Apala |
Instruments | Drums, percussion, djembe |
Years active | 1959–2003 |
Labels | Columbia, CBS, Narada, Virgin, EMI, Chesky |
Website | olatunjimusic.com |
Kutukutu ayé rẹ
àtúnṣeOlatunji jẹ ọmọ bíbí ìlú Ajido, ni èbá Badagry, Lagos State, ni guusu iwọ-oorun Nigeria. ọkàn lára Ogu people, a ṣe àfihàn Olatunji sí orin ìbílẹ̀ ní áfríkà ni tete ọjọ ori. Orúkọ rẹ , Bàbátúndé, tunmọ sí 'baba tí dé', nítorí a bi lẹhin oṣù Méjì tí bàbá rẹ̀ kú, eni Ogu (Egun) ọkunrin, Zannu kú, a sì pé Olatunji ni Bàbátúndé reincarnation. Baba re je apẹja father to fẹ jẹ olóyè chieftain, iya re sí je amọkoko ti ọ jẹ ọkan lára ọmọ Ogu people. Olatunji lati ma so ède Gun (Ogu/Egun) ati Yoruba language. Ìyá ìyá rẹ àti ìyá ìyá rẹ - ìyá àgbà je alufa ti Vodun ati ìgbàgbọ Ogu,wo má sìn Vodun, bí Kori, ti ọ jẹ oriṣa ti irọyin.[2][3] nitori ikú bàbá rẹ̀ of his father's , ni tete ọjọ ori a kò láti jẹ oyè gẹgẹ bí olóyè .
Ni ọmọ ọdún méjìlá, o mọ pé ohun o fe di olóyè. O ka ìwé Reader's Digest ìwé ìròyìn nípa Rotary International Foundation's scholarship program, ti ọ sí kó ìdánwò rẹ . A gbà wọlé ọ lọ sí ilé ìwé gíga United States of America ni ọdún 1950.
Èkó
àtúnṣeOlatunji gbà Ebun ìwé o fẹ ni ọdún 1950 o sí ka ìwé Morehouse College ni Atlanta, Georgia, níbití o ni èròngbà, sùgbón kó korin Morehouse College Glee Club. Olatunji je ọrẹ gidigidi sí oludari Glee Club Dr. Wendell P. Whalum o so'wopo láti dá egbé akọrin choir's repertoire, "Betelehemu", orin keresimesi Naijiria . Lẹyìn tí ọ jade ni ile iwe Morehouse, o tẹsiwaju sí New York University láti kà nípa public administration. Níbi tí ọ ti bẹrẹ, egbé onílù kékeré láti má pa owó bi ọ ṣe tẹsiwaju ninu iwe re .[4]
- ↑ "The Nigerian drummer who set the beat for US civil rights". BBC News. 2020-09-01. Retrieved 2020-09-05.
- ↑ Olatunji, Babatunde; Atkinson, Robert (2005). The Beat of My Drum: An Autobiography. ISBN 9781592133543. https://books.google.com/books?id=U6xiXqGm49IC&q=akinsola+akiwowo&pg=PA6.
- ↑ Martin, Andrew R.; Matthew Mihalka Ph, D. (September 30, 2020). Music around the World: A Global Encyclopedia [3 volumes]: A Global Encyclopedia. ISBN 9781610694995. https://books.google.com/books?id=wvb2DwAAQBAJ&q=zannu+olatunji&pg=PA625.
- ↑ "Babatunde Olatunji 1927 – 2003". African Music Encyclopedia. May 2003. Archived from the original on June 5, 2011. Retrieved June 6, 2011. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)