Michel Martelly
Michel Joseph Martelly (ojoibi 12 February 1961), bakanna bi oruko ori itage re "Sweet Micky", ni Aare orile-ede Haiti lowolowo leyin to bori ninu idiboyan aare 2011[1]. Ko to di oloselu, Martelly je olorin ati onisowo. [2]
Michel Martelly | |
---|---|
President of Haiti | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 14 May 2011 | |
Alákóso Àgbà | Jean-Max Bellerive |
Asíwájú | René Préval |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 12 Oṣù Kejì 1961 Port-au-Prince, Haiti |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Farmers' Response Party |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Sophia Martelly |
Àwọn ọmọ | 4 |
Profession | Musician Composer |
Sweet Micky | |
---|---|
Orúkọ àbísọ | Michel Joseph Martelly |
Irú orin | Compas music |
Occupation(s) | Musician Composer |
Instruments | Vocals Keyboard |
Years active | 1988–2011 |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ "Singer "Sweet Micky" takes oath as Haiti's president". Reuters. Retrieved May 14, 2011.
- ↑ Miller, Michael E. "Sweet Micky's masquerade ...the musician has a dark side" Archived 2011-08-10 at the Wayback Machine. Miami New Times. Jun 09, 2011. Retrieved Jun 07, 2011.