René Garcia Préval (ìpè Faransé: ​[ʁəne pʁeval]; born January 17, 1943) je oloselu ara orile-ede Haiti to je Aare orile-ede Haiti lati May 2006 de 14 May, 2011. Teletele, o tun ti je Aare lati February 7, 1996, titi di February 7, 2001, ati gege bi Alakoso Agba lati February 1991 titi di October 11, 1991.

René Préval
President of Haiti
In office
14 May 2006 – 14 May 2011
Alákóso ÀgbàGérard Latortue
Jacques-Édouard Alexis
Michèle Pierre-Louis
Jean-Max Bellerive
AsíwájúBoniface Alexandre
Arọ́pòMichel Martelly
In office
7 February 1996 – 7 February 2001
Alákóso ÀgbàClaudette Werleigh
Rosny Smarth
Jacques-Édouard Alexis
AsíwájúJean-Bertrand Aristide
Arọ́pòJean-Bertrand Aristide
Prime Minister of Haiti
In office
13 February 1991 – 11 October 1991
ÀàrẹJean-Bertrand Aristide
AsíwájúMartial Célestin
Arọ́pòJean-Jacques Honorat
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí17 Oṣù Kínní 1943 (1943-01-17) (ọmọ ọdún 81)
Cap-Haïtien, Haiti
Ẹgbẹ́ olóṣèlúLespwa
(Àwọn) olólùfẹ́Geri Benoit (Divorced)
Solange Lafontant (Divorced)
Elisabeth Delatour (2009–present)
Alma materCollege of Gembloux
Catholic University of Leuven
University of Pisa
ProfessionAgronomist


Itokasi àtúnṣe