Michelle Attoh jẹ́ òṣèré orílẹ̀ èdè Ghana kan, olugbóhùn sáfẹ́fẹ́ lórí amóhùnmáwòrán àti Alakoso fún Marketing and Events company. [1] Wọ́n bíi sí orílẹ̀ èdè Ghana sínú ẹbí ògbóǹtarìgì òṣèré orílẹ̀ èdè Ghana, Rama Brew .

Michelle Attoh
Ọjọ́ìbíMichelle Attoh
Orílẹ̀-èdèGhana
Ẹ̀kọ́Unknown
Iṣẹ́Òṣèré, olugbóhùn sáfẹ́fẹ́ lórí amóhùnmáwòrán
Gbajúmọ̀ fúnEré ṣíṣe, Olóòtú fún TV Shows

Iṣẹ́ àtúnṣe

Michelle ni olóòtú Today's Woman lórí TV3 . Díẹ̀ nínú àwọn ipa mìíràn tí ó ti kópa nínú iṣẹ́ rẹ̀ ni a ṣe àkójọ sí ìsàlẹ̀.

Odun Akọle Ipa Awọn akọsilẹ
2019 Fix Us Oṣere
Ọdun 1990-2000 Ultimate Paradise Oṣere
N/A Home with Michelle Attoh Olóòtú
N/A Bad Luck Joe Oṣere

Àwọn ìtọ́kasí àtúnṣe

 

  1. "TheBFTOnline". Michelle Attoh to host new season of Today’s Woman on TV3. June 13, 2020. https://thebftonline.com/13/06/2020/michelle-attoh-to-host-new-season-of-todays-woman-on-tv3/.