Miraboi
Miracle Kelechi Chike (tí wọ́n bí ní March 24, ọdún 1998) tí àwọn ènìyàn mọ̀ sí Miraboi jẹ́ olórin ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, akọrinkalẹ̀, òṣèrékùnrin, onínúure àti oníṣòwò.[2] Àwọn òbí rẹ̀ wá láti Ipinle Abia, àmọ́ Ìpínlẹ̀ Èkó ló dàgbà sí, níbi tí ó sì ti bẹ̀rẹl iṣẹ́ rẹ̀.[3]
Miraboi | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Miracle Kelechi Chike 24 Oṣù Kẹta 1998 Lagos State, Nigeria |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ẹ̀kọ́ | Lasu Secondary School, MillBank Secondary, Rolex Comprehensive College |
Iléẹ̀kọ́ gíga | University of Port Harcourt |
Iṣẹ́ | Public relation, Singer, songwriter |
Musical career | |
Irú orin | Afrobeats |
Instruments | Vocals |
Labels | Miraboi Records |
Associated acts | Davido,[1] Zlatan, Lil Kesh, D-TAC, Holargold, Peruzzi, Fireboy DML |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Nigeria: Davido Is the King of African Music - Miraboi". All africa Newspaper. Archived from the original on 8 January 2020. Retrieved 8 January 2019.
- ↑ "I have no reason to hate anyone – Miraboi". Vanguard Newspaper. Retrieved 4 April 2020.
- ↑ "I focus more on entertainment than my school – Yung Miraboi Mark". The Sun Newspaper. Retrieved 13 November 2018.