Davido
David Adédèjì Adélékè tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ Davido tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kọkànlélógún oṣù kọkànlá ọdún 1992 (November 21st, 1992) jẹ́ gbajúmọ̀ olórin ìgbàlódé ọmọ bíbí ìlú Ẹdẹ ní ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà.[1]
Davido | |
---|---|
Davido performing at the 2020 Lagos City Marathon gala | |
Background information | |
Orúkọ àbísọ | David Adedeji Adeleke |
Ọjọ́ìbí | 21 Oṣù Kọkànlá 1992 Atlanta, Georgia, US. |
Irú orin | |
Occupation(s) |
|
Years active | 2010–present |
Labels |
|
Associated acts | |
Website | iamdavido.com |
Àdàkọ:Infobox YouTube personality |
Davido gba àmì ẹ̀yẹ Next rated Award ni ọdun 2012 ni à kó jo “The Headies ní èyìn ìgbà tí o kọ Orin “Dami Duro”, tí ó jẹ́ orin kejì ní nú àkópo orin rẹ̀ “Omo Baba Olowo” 2012. Láàrin Ọdún 2013 àti 2015, ó ṣe àkójáde oríṣiríṣi orin tí ó jẹ́ ìlú mọ̀ọ́nká ní ọdún 2016 ó ki ọwọ́ bọ̀wé pẹ̀lú ará ilé-iṣẹ́ olórin àgbáyé Sony Music. Ní ẹ̀yìn ìgbà náà ó dá ilé- iṣẹ́ orin ti ẹ̀ sílẹ̀ Davido Music Worldwide (DMW), pẹ̀lu àwọn olórin bíi Dremo, Mayorkun, Peruzzi pẹ̀lú Liya tí wón wà lá bẹ̀ ẹ̀. Ní ọdun 2016, Davido tún ki ọwọ́ bọ̀wé pẹ̀lú ilé-iṣẹ́ olórin Sony RCA Records. Ní oṣù kẹwàá ọdún 2016 óṣe orin pélébé aláwo márùn-ún sí ta “Son of Mercy”, pẹ̀lú àwọn orin ọlọ́kan-ò-jọ̀ kan bíi "Gbàgbé Òṣì ", "How Long" and "Coolest Kid in Africa". Ní Oṣù kẹrin 2017, Davido tún dúnàá-dúrà pẹ̀lú ìkọwọ́ bọ̀wé pẹ̀lú Sony nítorí à
atè íeni ágbaró loàwọn won orií ó i oọiṣá úají ọi ́n oáà, ó sìosún tọuo oriárùn-ún run bi "If" and "Fall".[2] "If" generated worldwide social media activity while "Fall" became the longest-charting Nigerian pop song in Billboard history.[2][3] Davido has been famously referred to as 'The king of modern-day afrobeats'.[4][5]
Davido se ase sita akojo orin keji A Good Time ni osu kokanla odun 2019, pelu Orin bi "Blow My Mind" pelu ohun korin ilu moka Amerika Chris Brown . Davido je okan pataki ti won tokasi larin awon “Top 100 most influential Africans” ti o mo yan New African magasin in 2019.[6] He released his third studio album A Better Time, on Friday 13 November 2020. As at August 2021, Davido is the second most followed African on the social media app Instagram.[7][8]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ The Nigerian Voice (2018-09-16). "Davido Kicks Off Uncle's (Sen. Adeleke) Campaign In Ede. (Photos & Video)". Nigeria HomePage. Retrieved 2020-01-04.
- ↑ 2.0 2.1 "OBO is the hottest Nigerian musician of 2017". Pulse Nigeria. December 12, 2017. Archived from the original on March 1, 2019. Retrieved March 1, 2019. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Damola Durosomo (February 6, 2019). "Davido's 'Fall' Is the Longest-Charting Nigerian Pop Song in Billboard History". OkayAfrica. Archived from the original on March 1, 2019. Retrieved March 1, 2019. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Johnston, Kathleen (9 December 2019). "Davido: 'Ten years ago it wasn't cool to be African, but now it's all changed'". British GQ. British GQ (British GQ) (Music). https://twitter.com/britishgq/status/1204321633974050818.
- ↑ Insights, Music Industry. "A Talk with Davido, the King of Afrobeats". Midem. Midem Africa. Archived from the original on 2 February 2022. Retrieved 23 August 2021.
- ↑ Africa, Ventures (2019-10-09). "Top 10 Nigerians in Africa Report's 100 most influential Africans". Ventures Africa (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-01-15.
- ↑ Olli, Mag. "Top 10 Most Followed African Celebrities on Instagram". Ollimag. Ollimag. Archived from the original on 1 February 2022. Retrieved 23 August 2021.
- ↑ Amina, Wako. "Nigeria: Davido Officially Becomes Most Followed African Artist On Instagram". AllAfrica. Nairobi News. Retrieved 23 August 2021.