Mo'Nique
Monica Imes (ojoibi December 11, 1967), to gbajumo bi Mo'Nique, je àlawada ati óṣere lóbinrin ara Amerika to gba Ebun Akademi bi Obinrin Osere Keji Didarajulo[1][2].
Mo'Nique | |
---|---|
Mo'Nique at the 2010 16th Screen Actors Guild Awards | |
Ọjọ́ìbí | Monica Imes 11 Oṣù Kejìlá 1967 Woodlawn, Baltimore County, Maryland |
Orúkọ míràn | Mo |
Iṣẹ́ | Actress Comedienne Talk show host Author |
Ìgbà iṣẹ́ | 1999–present |
Olólùfẹ́ | Mark Jackson (m. 1997–2001) Sidney Hicks (m. 2006–present) |
Website | moniqueworldwide.com |
Igbèsi Àyè Arabinrin naa
àtúnṣeMo'Nique ni a bini Woodlawn, Baltimore County ni Maryland. Óṣere lobinrin naa jẹ ọmọ Alice Imes (Engineer) ati Steven Imes (Ólúbadamọran ti ogun)[3].
Ki Mo'Nique to di Óṣère lóbinrin ni ó ṣiṣẹ gẹgẹbi Customer Service Representative ni Ilè iṣẹ ẹrọ imulèwọ MCI ni Hunt Valley, Maryland. Mo'Nique fẹ accountant Kenny Mung fun igbà rànpẹ. Óṣèrè lobinrin naa fẹ Mark Jackson ni ọdun 1991 di 2001 ti wọn si bi ọmọ ọkunrin meji; Mark Eric Jackson Jr. ati Shalon Calvin Jackson. Mo'Nique bi Ibeji ọkunrin meji Jonathan ati David Hicks ni óṣu October ọdun 2005 fun Sidney Hicks ti wọn si fẹ ara wọn ni ọdun 2006[4].
Ẹkọ
àtúnṣeMo'Nique jade ni Milford Mill High School ni ilu Baltimore County ni ọdun 1985 ati Ilè iwè giga ti Morgan. Óṣere lóbinrin naa jẹ ẹni to kawe ja ni ọdun 1987 ni Institute Iróyin ti Maryland[5].
Ipa Óṣere lobinrin ninu Èrè Àgbèlèwó
àtúnṣeFilm
àtúnṣeỌdun | Akọlè | Ipa Óṣèrè lobinrin ninu èrè àgbèlèwó | Akiyesi |
---|---|---|---|
2000 | 3 Strikes | Dahlia | |
2001 | The Queens of Comedy | Herself | |
Baby Boy | Patrice | ||
Two Can Play That Game | Diedre | ||
2002 | Half Past Dead | Twitch's Girl | |
2004 | Soul Plane | Jamiqua | |
Hair Show | Peaches | ||
Garfield: The Movie | Rat | Role deleted in final cut of the film | |
2005 | Shadowboxer | Precious | |
Domino | Lateesha Rodriquez | ||
2006 | Farce of the Penguins | Vicky | Voice |
Irish Jam | Psycho | ||
Phat Girlz | Jazmin Biltmore | ||
Beerfest | Cherry | ||
2008 | Welcome Home, Roscoe Jenkins | Betty | |
2009 | Stepping: The Movie | Aunt Carla | |
Precious | Mary Lee Johnston | Won the Academy Award for Best Supporting Actress[6] | |
2014 | Blackbird | Claire Rousseau | |
2015 | Bessie | Ma Rainey | |
2016 | Interwoven | Barbara | |
Almost Christmas | Aunt May | ||
2022 | The Reading | Emma Leeden | Post-Production |
The Deliverance | Post-Production |
Television
àtúnṣeỌdun | Àkọlè | Ipa Óṣere lobinrin ninu èrè àgbèlèwó | Àkiyèsi |
---|---|---|---|
1999–2000 | Moesha | Nicole "Nikki" Parker | 3 episodes) |
2001 | The Hughleys | Nicole "Nikki" Parker | 1 episode) |
2002 | The Proud Family | Boonnetta (voice) | 1 episode) |
2003 | Good Fences | Ruth Crisp | Television film |
2004 | The Bernie Mac Show | Lynette | 1 episode) |
1999–2004 | The Parkers | Nicole "Nikki" Parker | 5 seasons, 110 episodes) |
2005 | Girlfriends | Host/Herself | Cameo (episode S5 E16) |
2006 | Rugrats | Aunt Moo | Direct-to-DVD episode "Tales from the Crib: Three Jacks and a Beanstalk" |
2006 | Nip/Tuck | Evetta Washington | 1 episode) |
2007 | Flavor of Love Girls: Charm School | Host/Herself | 11 episodes |
2007 | The Game | Plus Size Actress, Host | 2 episodes) |
2007 | The Boondocks | Jamiqua (voice) | 1 episode) |
2007 | Ugly Betty | L'Amanda | 1 episode) |
2009–2011 | The Mo'Nique Show | Host/Herself | 2 seasons, 251 episodes |
2014 | Love & Hip Hop: New York | Host/Herself | 2 episodes – Reunion Special) |
2015 | Bessie | Ma Rainey | Television film |
Residency show
àtúnṣe- 2019: Mo'Nique Does Vegas (held at SLS Las Vegas)[7]
Ami Ẹyẹ ati Idanilọla
àtúnṣeMo'Nique gba Àmi ẹyẹ Akademi, Àmi ẹyẹ BAFTA, Àmi ẹyẹ Golden Globe, Àmi ẹyẹ Emmy, Àmi ẹyẹ Óṣere Screen Guild ati Àmi ẹyẹ Oscar[8][9].
Itokasi
àtúnṣe- ↑ https://lasvegasweekly.com/ae/2019/jan/10/monique-comedy-residency-sls-sayers-club/
- ↑ https://www.hollywoodreporter.com/tv/tv-news/monique-show-put-indefinite-hiatus-217730/
- ↑ https://www.filmibeat.com/celebs/mo-nique.html
- ↑ https://web.archive.org/web/20080131132627/http://www2.oprah.com/tows/slide/200801/20080128/slide_20080128_350_206.jhtml
- ↑ https://web.archive.org/web/20110227034515/http://www.bim.org/news.php
- ↑ "82nd Oscars highlights". Oscars.org | Academy of Motion Picture Arts and Sciences (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2014-09-05. Retrieved 2020-07-12.
- ↑ Brock Radke (2019-01-10). "MO'NIQUE KICKS OFF HER FIRST VEGAS COMEDY RESIDENCY AT SLS". lasvegasweekly.com. Retrieved 2019-02-12.
- ↑ https://www.oscars.org/videos-photos/82nd-oscars-highlights
- ↑ https://variety.com/2022/tv/news/monique-netflix-comedy-special-1235319158/