Moses Ọláìyá Adéjùmọ̀
Moses Ọláìyá Adéjùmọ̀ (1936 - 2018) je gbaju gbaja osere ori amohun-maworan ati oni sinima omo ile Naijiria
Ohun ni opo eniyan mo si "Baba Sala". O je Alawada kerikeri elere ori itage Yoruba.
Moses Olaiya | |
---|---|
Ìbí | Moses Olaiya Adejumo 18-05-1936 |
Aláìsí | 7-10-2018 |
Àwọn orúkọ míràn | Baba Sala |
Àwọn ọmọ | Emmanuel Adejumo[1] Oyindamola Adejumo [2] |
Moses Adejumo je omo ilu Ijesha ni ipinle Osun.Baba Sala ni a gba pe o je Oludasile awada (Comedy) ninu ere Sinima ile Yoruba, gege bi o se ba awon ogbon-tagi osere ori itage Yoruba miran bii: Hubert Ogunde, Kola Ogunmola, Oyin Adejobi ati Duro Ladipo bi o se je wipe awon ni won pile ti won si gbe ere Sinima ori itage Yoruba gun oke agba doni, bakan naa ni o je oun paapaa mu idagba-soke ba Sinima Yoruba lapapo ni ilana tire naa.
Awon akojopo ere re
àtúnṣe- Orun Mooru (1982)
- Aare Agbaye (1983)
- Mosebolatan (1985)
- Obee Gbona (1989)
- Diamond (1990 Home video )
- Agba Man (1992, Home Video)
- Return Match (1993, Home Video)
- Ana Gomina (1996, home video, )
- Tokunbo (1985, TV)
Itoka
àtúnṣe- ↑ Abodunrin, Akintayo. "Feast of drama for the dramatist". 234NEXT.com. Retrieved 2009-09-19.
- ↑ "Gospel". African Gospel Music Center. Retrieved 2009-09-19.
External links
àtúnṣe- Film database
- African Video Collections Archived 2017-04-29 at the Wayback Machine. at Harvard College Library
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |