Motolani Alake
Motolani Olusegun Alake, tí a mọ̀ nípa iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀ sí Motolani Alake, jẹ́ agbẹjọ́rò ọmọ orílẹ̀-èdè Naijiria, ọ̀gá olórin, oníṣòwò, sọ̀rọ̀sọ̀rọ̀, akọ̀ròyìn, olóòtú podcast, àti olóòtú amóhùn-máwòrán. Ó sì tún jẹ́ alásọyé àṣà ìgbàlódé. Ó jẹ́ olóòtú àgbà ní Pulse Nigeria[1] láti oṣù kẹta ọdún 2022 títí di oṣù kejìlá ọdún 2022.[2] Lọ́wọ́lọ́wọ́, ó jé gíwá ilé-iṣé Nigeria TurnTable tó ń ṣamojútó orin orí àtẹ Afro-Pop tó gbégbá orókè. Àwọn ìgbìmọ̀ African Union gba Alake láti darapọ̀ mọ́ All Africa Music Awards, gẹ́gé bí ọ̀kan nínú àwọn aláwòfìn-ín fún Ìwọ̀-Oòrùn ilẹ̀ Africa ní ọdún 2022.[3][4][5][6][7]
Motolani Alake | |
---|---|
Orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Iṣẹ́ |
|
Gbajúmọ̀ fún | Pulse Nigeria |
Title |
|
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Motolani Alake". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 29 January 2023.
- ↑ Ajasa, Olufemi. "10 Things to know about Nigerian Music Executive, Motolani Alake". Vanguard Nigeria. Retrieved 28 February 2023.
- ↑ Obinna, Emelike (19 August 2022). "AFRIMA 2022: Adjudication commences as jury arrives Lagos". Businessday NG. Retrieved 29 January 2023.
- ↑ Team, Pride (21 November 2022). "Man Crush Monday: Motolani Alake". Pride Magazine Nigeria. Retrieved 30 January 2023.
- ↑ Oriowo, Ayomide (4 September 2022). "TurnTable Power List of the Top 30 Music Executives of H1 2022.". web.archive.org. TurnTable. Archived from the original on 4 September 2022. Retrieved 30 January 2023.
- ↑ Olukomaiya, Olufunmilola. "Music critic Motolani Alake named TurnTable Afro-Pop chart manager". P.M. News. Retrieved 17 February 2023.
- ↑ Oriowo, Ayomide. "Methodology and Policies for the TurnTable Nigeria Top 100". www.turntablecharts.com. TurnTable. Retrieved 30 January 2023.