Mr Real
Okafor Uchenna Victor, tí gbogbo ayé mọ̀ sí Mr Real, jẹ́ olórin ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó wá láti Ìpínlẹ̀ Èkó.
Mr Real | |
---|---|
Orúkọ àbísọ | Okafor Uchenna Victor |
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíi | Realself |
Ọjọ́ìbí | Lagos State, Nigeria |
Ìbẹ̀rẹ̀ | Ikeja, Lagos |
Irú orin | |
Occupation(s) |
|
Instruments | Vocals |
Years active | 2012–present |
Labels | SME Africa |
Associated acts |
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé ẹ̀
àtúnṣeMr Real tí a tún mọ̀ sí Real self ni a bí ní ọjọ́ kẹjọ, oṣù kẹjọ ní ìpínlẹ̀ Èkó, ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, sí àwọn òbí tí ó wá láti ìlú Okija, Ìpínlẹ̀ Anámbra.[1] Ó di gbajúgbajà lẹ́yìn tí ó gbé orin "Legbegbe" jáde.[2] Ó tọwọ́ bọ̀wé fún ṣíṣe ọ̀wọ́ orin pẹ̀lú Sony Music Entertainment Africa ní ọdún 2018.[3]
Àtòjọ orin ẹ̀
àtúnṣeÀwọn orin àdákọ
àtúnṣeYear | Song | Featured |
---|---|---|
2017 | Legbebe | Idowest, Oba Dice, Kelvin Chuks |
2018 | Overload | Mr Eazi & Slimcase |
2018 | Allow Me | Solidstar |
2020 | Baba fela |
Àwọn orin tí ó kópa nínú rẹ̀
àtúnṣeYear | Song | Artist | Featured |
---|---|---|---|
2017 | Issa Banger | D'banj | Slimcase |
2018 | Balu | CDQ | Idowest |
2018 | Normal Level | DJ Nana | Zoro |
2018 | Sisi | DJ Neptune | Small Doctor & Pasuma |
2018 | Masun | Jaywon | Idowest & Ichaba |
2018 | Upandan | Zoroswagbag | |
2018 | Kunta Kunte[4] | DJ Lambo |
Àtòjọ àwọn àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀
àtúnṣeYear | Award ceremony | Award description | Result | Ref |
---|---|---|---|---|
2018 | The Headies | Best Street-Hop Artiste | Wọ́n pèé | [5] |
Year | Award ceremony | Award description | Result | Ref |
2018 | Nigeria Entertainment Awards | Hottest Single of the year | Gbàá | [6] |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "I have been making music professionally for 10years, says Legbegbe crooner". Pulse ng. Archived from the original on 2018-11-01.
- ↑ "Legbegbe has nothing to do with Seun Egbegbe —Mr Real". Tribuneonlineng Newspaper. Archived from the original on 2019-08-08.
- ↑ "Mr Real, `Legbegbe’ crooner signs Sony Music record deal - Vanguard News" (in en-US). Vanguard News. 2018-04-26. https://www.vanguardngr.com/2018/04/mr-real-legbegbe-crooner-signs-sony-music-record-deal/.
- ↑ Ohunyon, Ehis. "DJ Lambo Kunta Kunte feat Small Doctor x Mr Real" (in en-US). Archived from the original on 2018-11-08. https://web.archive.org/web/20181108184910/https://www.pulse.ng/entertainment/music/dj-lambo-kunta-kunte-feat-small-doctor-x-mr-real-id8649699.html.
- ↑ "Headies 2018: Full list of nominees". The punch newspaper. Retrieved 13 April 2018.
- ↑ "Nigerian Entertainment Awards 2018: Complete list of nominees". Music In Africa. Retrieved 12 September 2018.