Robert Mugabe

(Àtúnjúwe láti Mugabe)

Robert Gabriel Mugabe (Pípè ní èdè Shona[muɡaɓe], English: /mʊˈɡɑːbeɪ/ moo-GAH-bay; ojoibi 21 Oṣù Kejì 1924 - 6 Oṣù Kẹ̀sán 2019) jẹ́ ààrẹ orílẹ̀ èdè Zimbabwe tẹ́lè. Ó jẹ́ ìkan lára àwọn ajàgbòmìnira fún orílẹ̀ èdè Zimbabwe. Ó jẹ́ alákóso orílẹ̀ èdè yí láti ọdún 1980 sí 1987 kí ó tó di ààrẹ.[1]

Robert Mugabe
Ààrẹ orílẹ̀ èdè Zimbabwe tẹ́lè.
In office
31 December 1987 – 21 November 2017
Alákóso ÀgbàMorgan Tsvangirai
Vice PresidentSimon Muzenda
Joseph Msika
Joice Mujuru
John Nkomo
AsíwájúCanaan Banana
Arọ́pòEmmerson Mnangagwa
Prime Minister of Zimbabwe
In office
18 April 1980 – 31 December 1987
ÀàrẹCanaan Banana
AsíwájúAbel Muzorewa (Zimbabwe Rhodesia)
Arọ́pòPost abolished Revived 2009: Morgan Tsvangirai
Secretary-General of the Non-Aligned Movement
In office
6 September 1986 – 7 September 1989
AsíwájúZail Singh
Arọ́pòJanez Drnovsek
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí(1924-02-21)21 Oṣù Kejì 1924
Kutama, Salisbury, Southern Rhodesia
Aláìsí6 Oṣù Kẹ̀sán 2019 (ọmọ ọdún 95)
Ẹgbẹ́ olóṣèlúZANU-PF (1987-2017)
ZANU (1963–1987)
ZAPU (1961–1963)
(Àwọn) olólùfẹ́Sally Hayfron (deceased)
Grace Marufu
Alma materUniversity of Fort Hare
University of Oxford
University of South Africa
University of London
Signature

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Chan, Stephen (2003). Robert Mugabe: A Life of Power and Violence. p. 123.