Ìṣí ojúewé ètò àkọ́kọ́
3 × 4 = 12, a le to ami mejila si ori ilagbolojo meta ti ikokan ni ami merin tabi si ori ilaninaro merin ti ikokan won ni ami meta.
Àmì ìsọdipúpọ̀.

Ìsọdipúpọ̀ je ise ninu mathematiki to n se igbega nomba kan pelu omiran. O je ikan ninu awon ona isiro merin to wa (àwon yioku ni ìròpọ̀, ìyọkúrò, àti pínpín).

Fun àwon nomba adaba isodipupo je iropo to nyipo. Fun apere isodipupo 3 pelu 4 (tabi 3 lona 4) se siro nipa riro 3 merin po mo ara won:ItokasiÀtúnṣe